Èdè Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ìmúkúrò àtúnyẹ̀wò 508500 ti 200.120.115.194 (ọ̀rọ̀)unconstructive editing
k replaced private character U+F00F with its most possible equivalent – (combining) grave
Ìlà 17:
Ọ̀kan pàtàkì lára àwọn èdè orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni èdè Yorùbá. Àwọn ìpínlẹ̀ tí a ti lè rí àwọn tó n sọ èdè Yorùbá nílẹ̀ Nàìjíríà norílẹ̀ èdè Bìní. Tógò àti apá kan ní Gúúsù ilẹ̀ Amẹ́ríkà bí i Cuba, Brasil, Haiti, àti Trinidad. Ní gbogbo orílẹ̀-èdè tí a dárúkọ, yàtọ̀ sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òwò ẹrú ni ó gbé àwọn ẹ̀yà Yorùbá dé ibè
 
Èdè Yorùbá jẹ́ èdè kan ti ó gbalẹ̀ tí ó sì buyì kákàkiri àgbáyé. Ìtàn sọ fún wa pé ní àgbáyé Kwa ní èdè Yorùbá bátan; kwa jẹ́ iyè kan ní Niger Congo. A lèè sọ pé àwọn tí wọ́n ń sọ èdè Yorùbá yàtọ̀ sí orílẹ̀ èdè Nigeria lé ní Ọgbọ̀n nílíọ̀nùn, àwọn orílẹ̀ èdè tí a ti ń sọ èdè Yorùbá yàtọ̀ sí Nigeria ni. Togo, Ghana, Serria leone, Brazil, United Kingdom àti United State. Èdè Yorùbá, * pín sí orísirísi ẹ̀ka* ní àkọ́tán, ó sì ti di gbajúgbájà ni orílẹ̀ èdè Nìgeria àti àgbáláayé lá papọ̀. Àwọn nnkannǹkan tí ó ń gbé èdè Yorùbá níyì.
 
1. Òwe:- Orísirísi ọ̀nà ni a le gbà pa òwe:
Ìlà 35:
ÌLÒ ÈDÈ YORÙBÁ
 
Àwọn èròngbà kòòsí ìlò èdè Yorùbá yíì ni pé mo fẹ́ kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mọ èdè Yorùbá lo dáradára nítorí náà a wo ìjúba ni awùjọ Yorùbá, a wo ààtò, Ìtúmọ̀, ìlò, àti àgbéyẹ̀wò àwọn òwe, àkànlò èdè àti ọ̀rọ̀ àmúlò mííràn. A wo èdè àmúlò nígbà tí a bá ń sọ̀rọ̀ àti igba ti a ba kọ èdè Yorùbá silẹ. A wo ẹ̀bùn sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀. A sí wo ìlànà ati òté tó de sísọ̀rọ̀ ni àwùjọ Yorùbá. A wo ìwúrẹ láwùjọ Yorùbá. A wo aáyan àròkọ kikọ. Lábẹ́ àròkọ, a wo arokọ wọ̀nyí: alapejuwe, ajemọroyin, alalaye, alariiyan, ìsòròngbèsììsòròǹgbèsì, onisiipaya, ajẹmọ́-ìsonísókí-ìwé ati arokọ onileta. A wo bi a ṣe n se agbekale isẹ to da le girama, iwe atumọ, ọ̀rọ̀ àpilẹ̀kọ, àbọ̀ ìpàdé, ìjábọ̀ ìwádìí, ìwé ìkéde pélébé àti eyí ti a fi n se ìpolongo ti a máa ń tẹ̀ mọ́ ara ògiri. Èdè Yorùbá ni ibamu pẹlu asa obínibí Yorùbá. Ó yẹ kí a mọ ọ̀rọ̀ í dá sí. Ó yẹ ki a mọ ọ̀rọ̀ sọ, ki á si mọ ọ̀rọ̀ ọ́ kọ sílẹ̀ lẹ́yìn ìgbà ti a bá ka ìwé kékeré yìí.
 
BÍ ÈDÈ YORÙBNÁ SE DI KÍKỌ SÍLẸ̀