Orílẹ̀-èdè Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k Poarps ṣeyípòdà ojúewé Orile-ede YorubaOrílẹ̀-èdè Yorùbá
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 1:
[[ÀKÀNDÉ SAHEED ADÉBÍSÍ]]
 
[[ORÍLÈORÍLẸ̀-ÈDÈ YORÙBÁ]]
Yorùbá gégégẹ́gẹ́OrílèOrílẹ̀-Èdè jéjẹ́ àti-ìran-díran Odùduà pèlúpẹ̀lú gbogbo àwonàwọnwonwọn ń sin OlorunỌlọrun ni ònàọ̀nà ti Odùduà ń gbà sìn-ín; ti wonwọn si bá a jade kúrò ni agbedegbede ìwòìwọ̀ oòrùn nígbà tí ìrúkèrúdò dé nipa ìgbàgbóìgbàgbọ́ rèrẹ̀ yìí. Akikanjú yii pinnu láti lolọ tetẹ orílèorílẹ̀ èdè miran dó nibi tí wonwọn yóò gbé ni ànfàníàǹfàní ati sin OlorunỌlọrun ni ònàọ̀nà ti wonwọn gbà pé ó tótọ́ ti ó si yeyẹ. Bí wonwọn ti ń rìn káàkiri ni Yorùbá, bí OrìlèOrìlẹ̀-Èdè n gbòòrò síi, ti ó si fi jéjẹ́ pé l’onii gbogbo àwonàwọn ènìyàn tí wonwọn ń bá ni gbogbo ibi tí wonwọn ti ń jagun tí ó di ti wonwọn àti ibi tí wonwọn gbé seṣe àtìpó, tí wonwọn si gbé gba àsààṣà, ati ìseìṣe wonwọn, titi ti okunrinọkunrin Akíkanjú, AkoniAkọni, OlùfokànsìnOlùfọkànsìn, Olóógun, Àkàndá èdáẹ̀dá, yii fi fi Ile-IfeIfẹ seṣe ibùjókòó ati àmù Yorùbá. Ile-IfeIfẹ yii si ni àwonàwọn Yorùbá ti fónkáfọ́nká kiri si ibi ti wonwọn gbé wà l’onii ti à ń pè ni ‘Ilè‘Ilẹ̀ K’áàròK’áàrọ̀, O jí i re’.
L’ónìí, kì í seṣe ibi tí a pè ni ‘Ìlè‘Ìlẹ̀ k’áàròk’áàrọ̀, O jí i ré’ yii nìkan ni àwonàwọn Yorùbá wà gégégẹ́gẹ́ bi èyàẹ̀yà kan. WonWọn fónfọ́n yíká IleIlẹ ènìyàn dudu ni, àti àwonàwọn orílèorílẹ̀-èdè mìíran l’ábérunl’ábẹ́run ayé.
 
Eyi ni ibi ti àwonàwọn èyàẹ̀yà ti à ń pè ni Yorùbá wà l’onii:
 
1. ORÍLÈORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ: ÌpínlèÌpínlẹ̀ ÒyóỌ̀yọ́, Ògún, Èkó, OndóOǹdó, Kwara, Èkìtì ati OsunỌṣun. A sì tún ń ri àwonàwọn Yorùbá diediediẹdiẹ ni àwonàwọn ìpínlèìpínlẹ̀ wonyiwọnyi:
 
(i) ÌpínlèÌpínlẹ̀ Kano: ÀwonÀwọn èyàẹ̀yà Yorùbá ti ó wà nibi ni àwonàwọn tí à ń pè ní ‘Báwá Yorúbáwá ati Gogobiri:
 
(ii) Sokoto: ÀwonÀwọn ìbátan wonwọn tí ó wà nibi ni à ń pè ni Beriberi. GégéGẹ́gẹ́ bi òwe ti ó wí pé ‘Oju ni a ti ń momọ dídùn obèọbẹ̀. Ilà oju àwonàwọn èyàẹ̀yà yii fi ìdí oroọrọ yii múlèmúlẹ̀.
 
(iii) ÌpínlèÌpínlẹ̀ IlèIlẹ̀ Ìbínní dé etí Odò OyaỌya: AwonAwọn wonyiwọnyi ni àwonàwọn ìlú tí omoọmọ Eweka gbé seṣe àtìpó ati ibi tí wonwọn jejẹ oyè sí, àwonàwọn bíi OnìsàOnìṣà Ugbó, OnìsàOnìṣà OlónàỌlọ́nà àti OnìsàOnìṣà Gidi (Onitsha), pàápàá jùlojùlọ àwonàwọnwonwọn ń jejẹ oyè tí à ń pè ni Òbí.
ÀwonÀwọn kan sì tún ni ìran Ègùn bíi:
 
Ègùn Ànùmí ni ileilẹ Tápà; Ègùn Àwórí ni ÈgbádòẸ̀gbádò; Ègùn Àgbádárígì ní ÌpínlèÌpínlẹ̀ Èkó.
 
2. ORÍLÉORÍLẸ́ ÈDÈ BENIN, TOGO, GANA ATI SÀRÓ
AwonAwọn ni Ègùn ileilẹ Kutonu, Ègùn Ìbàrìbá ileilẹ Benin; Aina, Aigbe àti Gaa ni ileilẹ Togo ati Gana; àti àwonàwọn Kiriyó (Creoles) ileilẹ Sàró (Sierra Leone).
 
3. ORÍLÈORÍLẸ̀ ÈDÈ AMÉRÍKÀAMẸ́RÍKÀ
ÀwonÀwọn orílèorílẹ̀ èdè tí ó wà l’áàrin AméríkàAmẹ́ríkà ti àríwá àti ti gúúsù (Cuba, Trinidad and Tobago, Jamaica and other Caribbean islands); ati àwonàwọn ÌpínlèÌpínlẹ̀ òkè l’ápá ìlà-oòrùn ti AméríkàAmẹ́ríkà ti Gúúsù: (Brazil, etc).
Bí ó tiletilẹ jéjẹ́àwonàwọn omoọmọ Odùduà tàn kálèkálẹ̀ bíi èèrùn l’ode oni, èríẹ̀rí wa pé orílèorílẹ̀ èdè kan ni wónwọ́n, ati pé èdè kan náà ni wonwọn ń sosọ nibikibi tí wonwọn lè wà. AhónAhọ́n wonwọnlólọ́ tàbí kí ó yí pada nínú ìsòròìsọ̀rọ̀ síi wonwọn, sùgbónṣùgbọ́n ìsesíìṣesí, ìhùwà, àsààṣà àti èsìnẹ̀sìn wonwọnyàtòyàtọ̀; gégégẹ́gẹ́àwonàwọn baba wa sì ti máa ń pa á l’ówe, a mòmọ̀ a sì gbà pé; Bi erúẹrú ba jojọ erúẹrú, ilé kan náà ni wonwọn ti wá’. AwonAwọn idi pàtàkì ti ahónahọ́n àwonàwọn omoọmọ Yorùbá fi yí pada díèdíẹ̀ díèdíẹ̀ díèdíẹ̀, bí ó tilètilẹ̀ jéjẹ́ pé èdè Yorùbá kan náà ni wonwọn ń sosọ niyi:
 
(a) Bí àwonàwọn akoniakọni ti ń jade kúrò ni Ilé-IfèIfẹ̀ láì pada bòbọ̀ wá sile mómọ́, ni wonwọn ń gbàgbé díèdíẹ̀ nínú èdè ìbínibí wonwọn.
 
(b) Ibikibi ti àwonàwọn akoniakọni yii bá sì seṣe àtìpó sí tàbí tèdótẹ̀dó sí ni wonwọn ti ń ba ènìyàn. OtitoOtitọ ni wonwọn gba orí l’ówól’ọ́wọ́ àwonàwọn ti wonwọn ń bá ti wonwọn sì ń di ‘Akéhìndé‘Akẹ́hìndé gba ègbón’ẹ̀gbọ́n’, sugbónṣugbọ́n bi wonwọn bá ti ń di onile ni ibi ti wonwọn tèdótẹ̀dó, tàbí ti wonwọn seṣe àtìpó si yii, ni wonwọndíèdíẹ̀-díèdíẹ̀ lò nínú èdè, àti àsààṣà wonwọn nitori pe bi ewé bá pépẹ́ lára oseọṣẹ bi kò tiletilẹ di oseọṣẹ yoo dà bí oseọṣẹ; àti pé ti ó bá pépẹ́ ti ÌjèsàÌjẹ̀ṣà bá ti jejẹ iyán, kì í momọ òkèlè èẹ̀mómọ́; òkèlè ti ó yeyẹ kí ó máa bù nlanla yoo di ródóródó. Eyí ni ó sì ń fa ìyàtòìyàtọ̀ díèdíẹ̀-díèdíẹ̀ nínú ìsesíìṣesí àwonàwọn Yorùbá nibikibi ti wonwọn bá wà l’ónìí.
 
(d) Bi àwonàwọn omoọmọ Yorùbá ti seṣe ń rìn jinna sí, sí Ile-IfeIfẹ ni ahónahọ́n àwonàwọn èyàẹ̀yà náà seṣe ń yàtòyàtọ̀. AwonAwọn tó gba onaọna òkun lolọ ń fofọ èdè Yorùbá ti ó lami, ti a sì ń dàpè ni ÀNÀGÓ, àwonàwọn ti wonwọn sì gba onaọna igbó àti òdànọ̀dàn lolọ ń sosọ ogidi Yorùbá, irú wonwọn ni a sì ń pè ni ará òkè.
 
Pàtàkì nínú àwonàwọn èyàẹ̀yà Yorùbá ti ó kúrò ni Ile-IfeIfẹ ti ó sì gba apá òkè lolọ nínú igbó ati òdànọ̀dàn niyi:
 
ÒyòỌ̀yọ̀; ÌjèsàÌjẹ̀ṣà; Àkókó; Èkìtì; ÒwòỌ̀wọ̀; OndóOǹdó; Ìgbómìnà; ÒfàỌ̀fà; ÌlorinÌlọrin; àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ. ÀwonÀwọn ti o si gba esèẹsẹ̀ odò lolọ ni ÈgbáẸ̀gbá; ÈgbádòẸ̀gbádò; ÌjèbúÌjẹ̀bú; ÌlàjeÌlàjẹ; IkaleIkalẹ àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ.