National Arts Theatre: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
k corr using AWB
Ìlà 1:
[[File:The National Arts Theatre in Lagos (7099736099).jpg|right|300px|The National Arts Theatre in Lagos, Nigeria]]
 
''' National Arts Theatre'''je ogan gan ibi ipate isere ori-itage ile [[Naijiria]] . Ile igbafe naa ni o kale si agbe gbe Iganmu, ni ijoba ibile  [[Surulere]], ni  [[Èkó|ipinle Eko]]. Won ko gbongan isere yii pari ni odun  1976 fun ipalemo ayeye akojopo ile Adulawo Meri ti (FESTAC) Festival of Arts and Culture  ni odun 1977. Awon akojopo ohun oso abalaye ati ti igba-lode ti ile Naijiria ni won ko sinu gbangan naa.
 
[[File:2009 National Arts Theatre Lagos Nigeria 6350723082.jpg|right|300px|The National Arts Theatre in Lagos, 2009]]
Ìlà 11:
 
== Yanpon-yanrin lori gbangan naa ==
Ni odun 2010, Aare igba naa, ogbeni  [[Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́|Olusegun Obasanjo]] kede re lati so gbangan nla naa di ti aladani . Eleyi ni o da idaru-dapo sile laarin awon osere amuluudun omo ile Naijiria ati awon akoni onkowo bii [[Wọlé Sóyinká|Wole Soyinka]] ko jale lati je ki Aare naa se bee. Ni ogbonjo 30 osu December 2014, won fi lede wipe won ti ta gbangan naa fun awon ajo ti won wa ni ile Dubai ni ogoji Milionu Dollar ($40million), ti won si so wipe won yoo so gbangan naa di ile itaja fun awon arinrin ajo, paa paa julo awon arinrin ajo lo soke.
 
== Awon itoka si ==