Ifá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 10:
== DÍẸ̀ LARA ÀWỌN OHUN ÈLÒ IFÁ DÍDÁ ==
 
Oríṣìíríṣìí ni àwọn ohun èlò tí àwọn babaláwo fi í da ifá ikin ifá ni àdáyéná nínú wọ́n. Ikin ifá jẹ́ mẹ́rìndínlógún. Ohun èlò ifá-dídá míìran ni ọ̀pẹ̀lẹ̀, èyí ló wọ́pọ̀ jù fún ifá dídá ní ayé òde òní. Àwọn babalàwo máa ńsábàá lo ikin ifá (èkùrọ́ ifá) nígbà tí wọ́n bá mbọ ifá ní ọọ̀dẹ̀ẹ̀ wọn, wọ́n a sì lo ọ̀pẹ̀lẹ̀ fun ará òdé tí ó wáá da ifá lọ́dọ̀ọ wọn láti ibi èso igi ọ̀pẹ̀lẹ̀ ni a ti ń mú ọ̀pẹ̀lẹ̀ ifá.
 
==='''Ikin ifá:'''=== Èyí jẹ́ mẹ́rìndínlógún. Àwọn mìíràn máa pè é ní èkùrọ́ ifá. Àwọn babalàwo máa ńsábàá lo ikin ifá tàbí èkùrọ́ ifá yìí nígbà tí wọ́n bá mbọ ifá ní ọọ̀dẹ̀ẹ̀ wọn, wọ́n a sì lo ọ̀pẹ̀lẹ̀ fun ará òdé tí ó wáá da ifá lọ́dọ̀ọ wọn
Ohun èlò ifá dídà míìran ní ìrọ́kẹ́ tàbí ìrọ́fá èyí jé ọ́á gbóńgbó kan báyìí tí a ńmú lu ọpọ́n ifá bí a bat í ńki ifà lọ àwọn olóyè ifá a máa fi ehín erin gbẹ́ ìrọ́kẹ́ẹ ti wọn.
 
===Ọ̀pẹ̀lẹ̀:=== Ohun èlò ifá-dídá míìran ni ọ̀pẹ̀lẹ̀, èyí ló wọ́pọ̀ jù fún ifá dídá ní ayé òde òní. Àwọn babalàwo máa ńsábàá lọ ọ̀pẹ̀lẹ̀ tí wọ́n bá fẹ́ dáfá fún ẹlòmíràn. Lára igi èso ọ̀pẹ̀lẹ̀ ni a ti ń mú ọ̀pẹ̀lẹ̀ ifá.
Ohun èlò ifá dídá míìran ọpọ́n ifá, nínú ọpọ́n ifá ni a ní lati kó gbogbo ohun èlò ifá dídá tí a ti ká sílẹ̀ wọnyìí sí bá a bá ti ńdá ifá. Orísi ọpọ́n ifá ló wà ọpọ́n kékeré wà, ọpọ́n ńlá sì wà pẹ̀lú.
 
===Ìrọ́kẹ́ Ifá:=== Ohun èlò ifá dídà míìran ní ìrọ́kẹ́ tàbí ìrọ́fá èyí jé ọ́á gbóńgbó kan báyìí tí a ńmú lu ọpọ́n ifá bí a bat í ńki ifà lọ. àwọnÀwọn olóyè ifá a máa fi ehín erin gbẹ́ ìrọ́kẹ́ẹ ti wọn.
Àwọn babaláwo a máa ní owó ẹyọ àti égúngún nínú ohun èlò ifá dídá wọn, owó ẹyọ dúró fún bẹ́ẹ̀ni, egungún sì dúró fún bẹ́ẹ̀ kọ nígbà tí a bá di ìbò béèrè nǹkan lọ́wọ́ ifá-owó-ẹyọ àti égúngún yìí tí a dì mọ́wọ́ ni à ń pè ni ìbò.
 
===Ọpọ́n Ifá:=== Ohun èlò ifá dídá míìran ọpọ́n ifá, nínú ọpọ́n ifá ni a ní lati kó gbogbo ohun èlò ifá dídá tí a ti ká sílẹ̀ wọnyìí sí bá a bá ti ńdá ifá. Orísi ọpọ́n ifá ló wà ọpọ́n kékeré wà, ọpọ́n ńlá sì wà pẹ̀lú.
Gbogbo ohun èlò ifa dídá tí mo kà sílè yìí ni a ńkó sínú àpò kan tí àwọn babaláwo ńgbé kọ́ èjìká báyìí tí à ń pè ni àpòo jèrùgbá, ẹnikẹ́ni tí o bá nkọ àpò yìí ni à ń pè ní akápò ifá tàbí babaláwò.
 
===Owó Ẹyọ Àti Egungun:=== Àwọn babaláwo a máa ní owó ẹyọ àti égúngúnegungun nínú ohun èlò ifá dídá wọn, owó ẹyọ dúró fún bẹ́ẹ̀ni, egungún sì dúró fún bẹ́ẹ̀ kọ nígbà tí a bá di ìbò béèrè nǹkan lọ́wọ́ ifá-owó-ẹyọ àti égúngún yìí tí a dì mọ́wọ́ ni à ń pè ni ìbò.
 
===Àpò Jẹ̀rùgbá:=== Èyí àpò tí àwọn [[Babaláwo]] máa ń kó gbogbo ohun èlò ifa dídá tí mo kà wọ̀nyí sí. Àwọn Babaláwo a máa gbé àpò Jẹ̀rùgbá kọ́ èjìká tí wọ́n bá ń re òde ifá.
 
== EBỌ IFÁ ==
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ifá"