Ifá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Mose afikun lori iwe yi
→‎ifá: moṣe atunṣe awon ami ori ọrọ nipa ifá
Ìlà 12:
Oríṣìíríṣìí ni àwọn ohun èlò tí àwọn babaláwo fìkí ifá ifá ni àdáyẹ̀na
 
Ìkín ifá:
knn
 
<br />
=== '''n ifá''' ===
 
=== '''n ifá''' ===
Èyí jẹ́ mẹ́rìndínlógún. Àwọn mìíràn máa pè é ní èkùrọ́ ifá. Àwọn babaláwo máa ń sábàá lo ikin ifá tàbí èkùrọ́ ifá yìí nígbà tí wọ́n bá ń bọ ifá ní ọọ̀dẹ̀ẹ̀ wọn, wọ́n a sì lo ọ̀pẹ̀lẹ̀ fún ará òdé tí ó wá dá ifá lọ́dọ̀ọ wọn
 
Line 36 ⟶ 38:
 
== Èṣù àti Ifá ==
Bí a ba wọ ilé àwọn babaláwo, a ó ri i wí pé ère [[Èsù]] kìí wọ́n nibẹ̀. Yangí ńlá kan o máa wà ní ẹ̀bá ilé àwọn babalawo. Yangí yìí dúró fún àmì Ẹ̀sù. Ìgbà gbogbo ni àwọn babaláwo máa gbé ẹbọọ lọ si ibẹ́, nwọn a máa bu epo lé yangí náà lórí, a máa rin sún nígbà gbogbo.
 
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ẹsẹ ifá tí o jẹ mọ Ẹ̀sù. Nígbà míìran, Èṣú jẹ́ ìrán ńṣé fún ifá. Nígbà miran ẹ̀wẹ̀, Èsú sí dá bí ẹni tí ńfún ifá ni agbára. Nínú ẹsẹ ifá a lè rí ohun tí o jọ bayin “…ni ọ̀rúnmìlà ba ti àṣẹ Èṣù bọnu”. ìtumọ̀ èyí ni wí pé bí ifá bá fẹ́ẹ́ ṣe nǹkan lile ti ó rí bí idan, àṣẹ Èṣù ló ní láti lò. Nígbà mìíràn, Èṣù jẹ́ olùrànlọ́wọ́ fún ifá. Nígbà mìíràn, Èṣù sì jẹ́ olùdánwò fún ifá.
Line 114 ⟶ 116:
Ọlọbọnhunbọnhun ni fapa ara rẹ dá gbẹ̀dú.
 
Níní
Ninu asa [[Yoruba]] '''Ifá''' A ti rí i ni ojú ewé 46 Apa Kini ìwe yi irú ipò pataki ti Orìṣà-nla tabi Ọbàtálá kó laarin awọn òrìṣà ati irúnmalẹ̀ ilẹ Yoruba. A ti gbọ́ pẹlu pe jákè-jádò gbogbo ilẹ̀ Yorùbá ni nwọn maa mbọ́ ọ́, nitoripe oun ni awọn àgbà àtijọ́ gbà ninu ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ wọn pe o jẹ igbákejì Olódùmarè, ti o si nràn an lọ́wọ́ lati tún enia dá nipa fífún un ni ojú, imú, eti, ati gbogbo ẹ̀yà ara miran ti o yẹ ki ẹ̀dá ní ki o fi lè di enia pipe. ...
 
ṣàà
 
à
 
Ninu asasa [[Yoruba]] '''Ifá''' A ti rí i ni ojú ewé 46 Apa Kini ìwe yi irú ipò pataki ti Orìṣà-nla tabi Ọbàtálá kó laarin awọn òrìṣà ati irúnmalẹ̀ ilẹ Yoruba. A ti gbọ́ pẹlu pe jákè-jádò gbogbo ilẹ̀ Yorùbá ni nwọn maa mbọ́ ọ́, nitoripe oun ni awọn àgbà àtijọ́ gbà ninu ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ wọn pe o jẹ igbákejì Olódùmarè, ti o si nràn an lọ́wọ́ lati tún enia dá nipa fífún un ni ojú, imú, eti, ati gbogbo ẹ̀yà ara miran ti o yẹ ki ẹ̀dá ní ki o fi lè di enia pipe. ...
 
== Iwe fun kika ==
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ifá"