Eartha Kitt: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
section heading; Reflist template
Ìlà 28:
 
Ní ọdún 1968, iṣẹ́ rẹ̀ ní Amẹ́ríkà rẹlẹ̀ lẹ̀yìn ìgbà tó [[Opposition to United States involvement in the Vietnam War|lòdì sí Ogun Vietnam]] nínú ọ̀rọ̀ tó sọ ní ibi àjọyọ ní [[White House]]. Ọdún mẹ́wàá lẹ́yìn náà, ó padà sí ṣeré nínú eré ìtàgé tó ṣe ní ọdún 1978 tó únjẹ́ ''[[Timbuktu!]]'', èyì tó gba ìkan nínú àwọn ìpèlórúkọ méjì [[Tony Award|Ẹ̀bùn Tony]] fún. Ìpè kejì fún Ẹ̀bùn Tony ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2000 fún ''[[The Wild Party (LaChiusa musical)|The Wild Party]]''. Kitt kọ ìwé-ìgbésíayé araẹni mẹ́ta.<ref>{{Cite book|last=Kitt|first=Eartha|title=I'm Still Here|year=1990|publisher=Pan|isbn=0-330-31439-4|location=London|oclc=24719847}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí ==
{{reflist}}
 
{{Commonscat|Eartha Kitt}}