Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ipa àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 lórí ilé-iṣẹ́ oúnjẹ"

(Created by translating the page "Impact of the COVID-19 pandemic on the food industry")
 
(Created by translating the page "Impact of the COVID-19 pandemic on the food industry")
[[Àjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020|Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19]] ti ní ipá lórí ile-iṣẹ ounje kari aye bi awọn ijọba orilẹ-ede ṣe gbe awọn ile-ounjẹ ati awọn ile igbafẹ tì lati lè di ìtànkálẹ̀ kokoro naa. Jakejado agbaye, awọn ero to n wọ ile-ounjẹ lojoojumọ ti dinku jọjọ ti a ba fi we iru akoko yii ni ọdun 2019. Títìpa ti wọ́n ti àwọn ile-ounjẹ pa ti ṣe akoba fun awọn ile-iṣe miran bii ipese ounjẹ, ile-ipọn'ti loriṣiriṣi ati oko'wo ọkọ ojú omi tó nkó àwọn oja kaakiri, oun pẹlu iṣẹ ọgbin. <ref name=":19">{{Cite news|url=https://www.bbc.com/news/business-52020648|title=How are food supply networks coping with coronavirus?|access-date=2020-03-26|language=en-GB}}</ref>
 
Awọn ohun ti o jẹ yọ lati ara àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ti da rudurudu silẹ ni awon agbegbe ti wọn ti n ko ounjẹ wọle pẹlu eto loju-ẹsẹ.
 
Ni Oṣu Kẹfa ọdun 2020, Àjọ awọn orilẹ-ede Agbaaye ([[Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè|United Nations]]) kìlọ̀ pé gbogbo ayé ń dojúkọ [[ Awọn iyan ti o ni ibatan ajakaye-arun COVID-19 |ìdààmú oúnjẹ ti o burú jùlọ]] lati bii idaji ọgọrun ọdun seyin nitori [[ Iṣeduro Coronavirus |ipadasẹhin oko'wo ti ajakaye-arun naa ti fa]] . <ref>{{Cite news|last1=Harvey|first1=Fiona|title=World faces worst food crisis for at least 50 years, UN warns|url=https://www.theguardian.com/society/2020/jun/09/world-faces-worst-food-crisis-50-years-un-coronavirus|accessdate=13 June 2020|work=The Guardian|date=9 June 2020}}</ref>
265

edits