Welcome to Yoruba Wikipedia and thanks for your contributions. Please, keep it up. T Cells (ọ̀rọ̀) 09:09, 24 Oṣù Kẹrin 2018 (UTC)

Mary SlessorÀtúnṣe

Ekuuse o,onise:Adefanike.Mo fe je ki e mo pe mo ti da atunse ti e sese se si ayoka oke yi pada nitori pe atunse yen kan da oju ewe ayoka yii ru ni. E jowo e ma a wo ayoka daadaa ki e to se atejade re ati pe kii se dandan ki e lo "content translation tool" ki e to se atunse si ayoka ti e ba n kolo tele. Eseun. T Cells (talk · contribs · email) 10:27, 28 Oṣù Keje 2018 (UTC)


QuestionÀtúnṣe

Hi Adefanike please how did you type yoruba from your keyboard Thanks