Wọlé Sóyinká: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 29:
Wọ́n bí Wọlé Sóyinká ní ìlú [[Abẹ́òkúta]], ní ìpínlẹ̀ Ògùn, Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní orílè-èdè Nàìjíríà àti [[United Kingdom]] tán, Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Theatre Royal Court ni ìlú Loọ́ńdọ̀nù (London). Ó tẹ̀ síwájú láti kọ àwọn eré oníṣe lorílẹ̀ èdè méjèèjì ní tíátà àti orí ẹ̀rọ Asọ̀rọ̀-mágbèsì. Ó kó ipa pàtàkì nínú ètò ìṣèlú àti akitiyan lópọ̀lọpọ̀ nínú ìjàǹgbara òmìnira orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]] kúrò lọ́wọ́ ìjọba amúnisìn [[Great Britain]].<ref name="Laureate. 1934">{{cite web | last=Laureate. | first=the | title=The Nobel Prize in Literature 1986 | website=NobelPrize.org | date=1934-07-13 | url=https://www.nobelprize.org/prizes/literature/1986/soyinka/biographical/ | access-date=2019-09-09}}</ref>
 
==Gallery ==
<gallery>
Image:Soyinka Festivaletteratura 2019.jpg|Wọlé Sóyinká, [[2019]], [[Mantova]]
</gallery>
 
{{ekunrere}}
== Àwọn Ìtọ́kasí ==
{{reflist}}