Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Bimbo Ademoye"

k
 
Ní Oṣù Kẹrin ọdún 2018, ó ṣe alábáṣìsẹ́pọ̀ pẹlu Stella Damasus nínú ''Gone'', tí Daniel Ademinokan ṣe olùdarí . Ó ṣe àpèjúwe ṣiṣẹ́ iṣé pẹ̀lú Damasus gẹ́gẹ́bí àkókò ìwúrí fún iṣẹ́ rẹ̀ . Ní [[2018 City People Movie Awards]] ,ó yàn fún Ìfihàn ti Ọdún, Òṣèré Tuntun Tuntun tó dára jù lọ àti Òṣèré àṣẹ̀ṣẹ̀bẹ̀rẹ̀ tó dára jùlọ. Ipa rẹ̀ nínu ''Backup Wife'' tún jẹ́ kí ó gba yíyàn fún '' Best Lead Role'' ní 2018' Nigeria Entertainment Awards. Ó gbà àwọn ẹ̀bùn méjì ní 2018 Best of Nollywood Awards fún ipa rè nínu' ''Personal Assistant'', ó sì gba ẹ̀bùn fún Òṣèré tí ó dára jùlọ nínú ipa àtìlẹ́yìn óssì gba yíyàn fún ''Best Kiss in a movie''.
 
==Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ ==
== Filmography ==
 
* ''Awọn ọrẹbinrin'' (2019)