Àdàkọ:Ayoka Ose/8: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
 
Ìlà 1:
[[File:Adeniran Ogunsanya.jpg|100px250px|left|Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]]]
'''[[Adeniran Ogunsanya]]''' [[Queen's Counsel|QC]], [[Senior Advocate of Nigeria|SAN]] (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]], tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú [[Ibadan Peoples Party (IPP)]]. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún [[Ìpínlẹ̀ Èkó]] ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú [[Nigerian People's Party]] nígbà ayé rẹ̀.
Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè [[Ìkòròdú]] ní [[Ìpínlẹ̀ Èkó]] sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti [[Hope Waddell Training Institute]] ní ìlú [[Calabar]] nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ [[King's College]] tí ó wà ní [[Ìpínlẹ̀ Èkó]] látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti [[Victoria University of Manchester|University of Manchester]] àti [[Gray's Inn]] tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.