Saidat Adegoke: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created by translating the page "Saidat Adegoke"
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 12:16, 8 Oṣù Kàrún 2021

Saidat Adegoke (ti a bi ni ojo kerinlelogun Osu Kẹsán Odun 1985 ni Ilorin, Ipinle Kwara, Nigeria ) jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede Naijiria.

Saidat Adegoke
Personal information
Ọjọ́ ìbí24 Oṣù Kẹ̀sán 1985 (1985-09-24) (ọmọ ọdún 38)
Ibi ọjọ́ibíIlorin, Kwara
Club information
Current clubLugano
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2011–2012FCF Como 2000
2008–2009Milan
National team
2010Nigeria
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Iṣẹ re

Ni odun 2007, Adegoke bere si ni gba boolu fun Remo Queens lati ilu re Naijiria, ni Serie A ti Orile ede Italy fun ACF Trento.

Leyin Serie A akoko ti o kopa fun Trento, o gba boolu wole sinu awon leemta ninu igba merindinlogun ti o kopa. Ni Osu kejo odun 2008, o koja si ACF Milan.

Ni Milan, itesiwaju baa, nigba ti o maa fi di odun 2011, o gba boolu wole sinu awon igba okanlelogun ninu igba mejilelaadota ti o kopa.

Ni igba ti boolu bere, ni bii odun 2011 si 2012, o koja si FCF Como 2000.

Lati ọdun 2010 o wa ninu ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede Naijiria ti awọn obinrin. [1]

Awọn itọkasi

 

  1. KASALOY SPORT: AC MILAN GOAL MONGER, SAIDAT AWAITS FALCONS INVITATION