Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba"

k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
k
Ikan ti mo mọ ti o si n jẹ ẹdun ọkan fun mi ni awọn ami-ohun ti mi o fi si ori awọn ayọka naa. Ko si n ṣe nitori nkan mii, sugbọn nitori wipe mi o ni imọ rẹ ni. Koda, mo ti kọ numba yin silẹ tẹlẹ ri lati kan si yin pe bi ẹ ba le ran mi lọwọ lori eyi, nitori mo ti wo awọn ayọka yin ti ẹ ti da ti mo ṣi ri wipe awọn ayọka naa da lami-ohun. [[Oníṣe:Osenibabalola0|Osenibabalola0]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Osenibabalola0|ọ̀rọ̀]]) 14:52, 2 Oṣù Kọkànlá 2020 (UTC)
 
:Ẹ ṣeun pupọ fun esi yin ati awọn imọran yin. Mo si kẹdun fun awọn iru ipenija bẹẹ ti ẹ n koju latari irufẹ awọn ayọka ti iru wa n da silẹ. Mo fi n da yin loju wipe maa gbiyanju lati ṣe atunṣe si awọn iṣẹ ti mo ti ṣe tẹlẹ, sugbọn mo ma nilo iranlọwọ yin gẹgẹ bi mo ti ṣe sọ siwaju. Maa kan si yin lori ila ipe yin gẹgẹ bi ẹ ti ṣe gba mi laye. [[Oníṣe:Osenibabalola0|Osenibabalola0]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Osenibabalola0|ọ̀rọ̀]]) 23:01, 2 Oṣù Kọkànlá 2020 (UTC)-
 
 
=== Atunse ti mo se ===
E kasan e ba mi moju to awon ise ti mo se oda bi pe awon citer o jade daadaa
Zend2020--[[Oníṣe:Zend2020|Zend2020]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Zend2020|ọ̀rọ̀]]) 09:52, 2 Oṣù Keje 2021 (UTC)
142

edits