Ọjà Ẹrù Veléketé: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
[[Fáìlì:SLAVE_MARKET,_Lagos.tif|right|thumb|270x270px| Oja Ẹrú, Badagry]]
'''Ọjà Ẹrù Veléketé''' jẹ́ ọjà tí ó wà ní [[Àgbádárìgì]] ní [[Ìpínlẹ̀ Èkó|Ìpínlẹ̀ Èkó]].<ref name="Tijani 2010 p.">{{cite book|last=Tijani|first=H.I.|title=The African Diaspora: Historical Analysis, Poetic Verses, and Pedagogy|publisher=Learning Solutions|year=2010|isbn=978-0-558-49759-0|url=https://books.google.com.ng/books?id=fdFPAQAAIAAJ|access-date=2021-08-06|page=}}</ref> Ọjà yí ni wón dá sílẹ̀ ní ọdún 1502 tí wọ́n sì wá a fi orúkọ òrìsà Veléketé pe ọjà yíi.<ref>{{Cite book|author=A. Babatunde Olaide-Mesewaku|title=Badagry district, 1863-1999|url=https://books.google.com/books?id=aJMuAQAAIAAJ|year=2001|publisher=John West Publications Ltd.|isbn=978-978-163-090-3}}</ref> Ọjà yí ṣe pàtàkì ní àkókò ìṣòwò ẹrù ti Trans-Atlantic ní [[Àgbádárìgì]] nítorípé ọjà yí dúró gégé bí ibi ààyè ìṣòwò níbití àwọn aláròóbọ̀, tí ó ma ńgba ẹrù tà, láti iléilẹ̀ [[Áfíríkà]] ti má ńta àwọn ẹrù fún àwọn oníṣòwò ẹrù tí wón wá láti ìlú [[Yúrópù]]. Èyí ló mú kí ọjà yí jé òkan nínú àwọn ọjà ẹrù tí ènìyàn inú rẹ pọ̀ jùlọ ní [[Ìwọòrùn Áfíríkà|Iwo-oorunÌwọòrùn AfirikaÁfíríkà]].<ref>{{Cite news|url=http://www.vanguardngr.com/2013/02/vlekete-when-a-slave-market-becomes-a-tourist-centre/|title=Vlekete: When a slave market becomes a tourist centre|author=Njoku}}</ref>
 
Ní ọdúnun 1805, Scipio Vaughan tí ó jẹ́ ọmọ abínibí Òwu ní ìlú Abéòkúta, orílè-èdè [[Nàìjíríà]], ni àwọn oníṣòwò ẹrù ti trans-Atlantic tí ó jẹ́ ilé [[Yúrópù]] mú, tí wọ́n sì gbe e lọ sí Ọjà Ẹrú Veléketé ní BàdágìrìÀgbádárìgì papọ́ pẹlú àwọn ẹrù miiran tí wón ti mú síwájú kí wọ́n tó wa fíi sínú ọkọ̀ ojú-omi tí wọn fi nkó àwọn ẹrù lọ sí ìlú Améríkà.<ref name="The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News 2020">{{cite web|title=Back-To-Africa: A Dying Wish Births A Living Legacy|website=The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News|date=2020-02-09|url=https://guardian.ng/life/back-to-africa-a-dying-wish-births-a-living-legacy/|access-date=2021-08-06}}</ref> .