E pele.

E jowo nigba ti e ba se atunse si ayoka, e je ki awon ajapo/links o wa. Demmy (ọ̀rọ̀)

.Àtúnṣe

Ẹ n lẹ́ níbẹ̀ yẹn o! Ṣówọlétọ̀yín, a kí yín, a yìn yín, a lù yín lọ́gọ ẹnu. A ń ṣàkíyèsí gbogbo iṣẹ́ àti akitiyan yín lórí ìkànì yí, ó sì ń wú wa lórí gidi gidi. A rọ̀ yín kí ẹ máa wá lóòrè kóòrè láti máa tẹ̀ síwájú nínú ojúlówó iṣẹ́ tí ẹ ń ṣe. A dúpẹ́ púpọ̀. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 21:29, 18 Oṣù Kẹta 2020 (UTC)Reply[ìdáhùn]

HiÀtúnṣe

How do you translate a whole content? Tell me.Tbiw (ọ̀rọ̀) 12:09, 26 Oṣù Keje 2020 (UTC)Reply[ìdáhùn]

Wikiversity Yoruba ProjectÀtúnṣe

Ku ojo, mo fẹ pẹ ọ lati darapo mo iranlowo idagbasoke Wikiversity Yoruba bi ọ ṣe duro lati jẹ ki ọ ṣee ṣe fun Wikipedia Yoruba darapo mo ise yi ko le ni aseyori. Fun alaye siwaju beere lọwọ mi ni oju-iwe oro mi tabi lo si oju-ewe ibeere fun ede titun ni ori Meta-Wiki.Tbiw (ọ̀rọ̀) 21:46, 31 Oṣù Kẹjọ 2020 (UTC)Reply[ìdáhùn]