M. K. O. Abíọ́lá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
#WPWP
k #NG
Ìlà 20:
==Igbesi Aye re==
Moshood Abíọ́lá ni àkọ́bí  bàbá àti ìyá rẹ̀ lẹ́yìn ìkúnlẹ̀ ọmọ kẹtàlélógún, ìdí èyí ní ó fàá tí wọ́n fi dúró títí di ẹ̀yìn ọdún mẹ́ẹ̀dógún (15 years) kí àwọn òbí rẹ̀ tó fún lórúkọ rẹ̀ “Kasimawo”<ref name="Odumakin 2018">{{cite web | last=Odumakin | first=Yinka | title=June 12 dissemblers | website=Vanguard News | date= | year=2018 | url=https://www.vanguardngr.com/2018/06/june-12-dissemblers/ | access-date=}}</ref> . Moshood fakọyọ nínú ìmọ̀ ìdágbálé (entrepreneur) láti ìgb̀a èwe rẹ̀, ó bẹ̀rè iṣẹ́ igi-ṣíṣẹ́ tà láti ọmọ ọdún mẹ́sàán. Ó ma ń jí ní ìdájí lọ sóko igi láti wági tí yóò tà ṣáájú kí ó tó lọ sị́ ilé-ìwé kí òun àti bàbá rẹ̀ tó ti rúgbo pẹ̀lú àwọn àbúrò rẹ̀ kó lè rówó ná. Nígb̀a tí ó t́o ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún (15 years), ó dá ẹgbẹ́ eré kan kalẹ̀ tí wọ́n ma ń kọrin kiri láti lè rí óúnjẹ jẹ níbi ìnáwo èyíkéyìí tí wọ́n bá lọ. Láìpẹ́, ó di gbajú-gbajà níbi orin rẹ̀ tó ń kó kiri, ó sì di ẹni tí ó ń bèrè fún owó iṣẹ́ kí wọ́n tó kọrin lóde ìnáwó kòkan. Àwọn owó tí ó ń rí níbi eré rẹ̀ yìí nị́ ó fi ń ran ẹbí rẹ̀ lọ́wọ́ tí ó sì ń san owó ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí ìjọ Onítẹ̀bọmi tí ó wà ní [[Abéòkúta]] . Abíọ́́lá jẹ́ Olóòtú ìwé ìròyìn ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ ilé-ìwé wọn tí ó ń jẹ́ [[The Trumpeter]] tí [[Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́]] sì jẹ́ igbákejì rẹ. Ó dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ [[National Council of Nigeria and the Cameroons]] ní ìgbà tí ó di ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún nítorí ìfẹ́ tí ó ní sí ètò òṣèlú àwa arawa lábẹ́ àsíá [[Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀]] olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú [[Action Group]].<ref name="Inyang 2018">{{cite web | last=Inyang | first=Ifreke | title=MKO Abiola: What Falana told Buhari about results of June 12 elections | website=Daily Post Nigeria | date=2018-06-12 | url=http://dailypost.ng/2018/06/12/mko-abiola-falana-told-buhari-results-june-12-elections/ | access-date=2018-06-13}}</ref>
 
Ni odun 1960, Moshood gba sikolashipu ijọba lati ka iwe ni University ti Glasgow ni ilu Scotland ni bii ti o gba oye ni isiro sebe sebe o o je oye oniṣiro iwiregbe. Moshood di Ẹlẹgbẹ ti Institute of Chartered Accountants of Nigeria (ICAN) (ICAN).
 
==Àwọn ìtọ́kasí==