Ìlú Ọ̀wọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
atunse
Ìlà 1:
'''Ilu Owo''' wa ni [[Ìpínlẹ̀ Òndó|ipinle Ondo]], guusu iwọ-oorun [[Nàìjíríà|Naijiria]], ni iha guusu ti awọn Oke ile [[Yorùbá|Yoruba]] (igbega 1,130 ẹsẹ ) ati ni ikorita awọn ọna lati [[Àkúrẹ́|Akure]], Kabba, [[Ìlú Benin|Ilu Benin]], ati Siluko. Cocoa je ikan lara awon oun ogbin ti o wopo ni ilu owo.<ref name="Encyclopedia Britannica 2009">{{cite web | title=Owo - Nigeria | website=Encyclopedia Britannica | date=2009-01-09 | url=https://www.britannica.com/place/Owo | access-date=2022-01-29}}</ref>
 
Owo je ikan lara awon ijoba ibile ni ipinle Ondo.<ref name="Olugbamila Adeyinka 2017 pp. 377–377">{{cite journal | last=Olugbamila | first=Omotayo Ben | last2=Adeyinka | first2=Samson Ajibola | title=Analysis of Socio-Economic Characteristics and Utilization of Healthcare Facilities in Owo Local Government Area of Ondo State, Nigeria | journal=European Scientific Journal, ESJ | volume=13 | issue=23 | date=2017-08-31 | issn=1857-7431 | doi=10.19044/esj.2017.v13n23p377 | pages=377–377 | url=https://eujournal.org/index.php/esj/article/view/9818 | access-date=2022-01-29}}</ref> Oba Owo ni won n pe ni olowo ti Ilu Owo. Oba ti o wa lori ite lowolowo ni [[Ajibade Gbadegesin Ogunoye]].<ref name="The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News 2019">{{cite web | title=Gbadegesin becomes new Olowo Of Owo - Nigeria and World News | website=The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News | date=2019-07-13 | url=https://guardian.ng/news/gbadegesin-becomes-new-olowo-of-owo/ | access-date=2022-01-29}}</ref>