Peter Obi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe lórí ẹ̀rọ alágbéká Android app edit
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe lórí ẹ̀rọ alágbéká Android app edit
Ìlà 27:
==Òsèlú==
Ni odun 2003, Obi díje fún ipò Gomina ìpínlè Anambra sùgbón o fìdíremi fún alatako rè, Chris Ngige, èni tí o jé oludije lábé egbé oselu People's Democratic Party(PDP), Obi gbé oro náà lo ilé ejó Court of appeal, nibi ti wón ti rojo oro náà fun odun meta koto dipe wón yo Chris Ngige nípò lati gbe Obi wolé ní osu Keta, odun 2006,, ni osu Kokanla odun 2006, àwon omo egbé ìgbìmò asofin ti ìpínlè Anambra yo Obi nípò gomina, wón si fi igba kejì rè, Virginia Etiaba sípò Gomina, èyi mú kí Virginia jé Gomina obinrin àkókò ni orílè-èdè Nàìjíríà.<ref name="The Mail & Guardian 2006">{{cite web | title=Nigeria's Anambra replaces impeached governor | website=The Mail & Guardian | date=2006-11-03 | url=https://mg.co.za/article/2006-11-03-nigerias-anambra-replaces-impeached-governor/ | access-date=2022-06-29}}</ref>Ilé ejó Court of Appeal tún da Peter Obi padà sipo Gomina, Virginia da agbara padà fún Peter Obi léyìn idajo ile ejó.<ref name="Reporters 2007">{{cite web | last=Reporters | first=Sahara | title=Peter Obi wins, he takes over! | website=Sahara Reporters | date=2007-02-08 | url=https://saharareporters.com/2007/02/08/peter-obi-wins-he-takes-over | access-date=2022-06-29}}</ref>
Ni osù karun 2007, Peter Obi tún fi ipò Gomina sílè léyìn tí Andy Uba wolé gegebi Gomina ìpínlè Anambra, o tori oro yìí lo ilé ejo lekansi, o ni sáà ijoba rè to ye kó bèrè bi odun 2003 kí o sì pari ni odún 2007 bèrè ní odun 2006, nitori náà, kí ilé ejó jé kí sáà ìjoba rè di odún 2010(kí ó ba le lo odún merin ìjoba rè pé). Ilé ejó ti Supreme Court ti Nàìjíríà fi ase sí òrò yìí, èyi tí o mu kí a yo Andy Uba kuro nípò Gomina Anambra
 
Ni ojo keje, osù kejì, odun 2010(7 Feb 2010), àjo INEC(Independent National Electoral Commission) kéde Peter Obi gegebi olùjáwé olúborí fún ipò Gomina ninú idibo odun 2010. Èyí mú kí Obi lo odún merin si nípò Gomina Anambra.<ref name="thisdayonline.com 2010">{{cite web | title=THISDAY ONLINE / Nigeria news / African views on global news | website=thisdayonline.com | date=2010-02-12 | url=http://www.thisdayonline.com/nview.php?id=165947 | archive-url=https://web.archive.org/web/20100212105816/http://www.thisdayonline.com/nview.php?id=165947 | archive-date=2010-02-12 | url-status=dead | access-date=2022-07-15}}</ref> Ni ojo 17 March 2014, Obi fi ipò Gomina kalè, Willie Obiano sì di Gomina ìpínlè Anambra nigbana.
 
Léyìn idibo gbogbogbo ti odún 2015, Ààré Goodluck Jonathan yan Peter Obi sípò alaga Nigerian Security and Exchange Commission(SEC).<ref name="Olajide 2015">{{cite web | last=Olajide | first=Bukky | title=Jonathan appoints Peter Obi chairman of SEC - Nigeria and World News | website=The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News | date=2015-04-28 | url=https://guardian.ng/news/jonathan-appoints-peter-obi-chairman-of-sec/ | access-date=2022-07-15}}</ref>
 
'''Idibo gbogbogbo odun 2019'''
 
Ni 12 October 2018, a yan Peter Obi gegebi ígbákejì oludije Atiku Abubakar, Atiku Abubakar jé olujide ipò ààré lábé egbé oselu People Democratic Party. Egbe oselu PDP gbé ipò keji ninú idibo gbogbogbo 2019.<ref name="Polycarp 2018">{{cite web | last=Polycarp | first=Nwafor | title=Breaking: Atiku picks Peter Obi as running mate | website=Vanguard News | date=2018-10-12 | url=https://www.vanguardngr.com/2018/10/breaking-atiku-picks-peter-obi-as-running-mate/amp/ | archive-url=https://web.archive.org/web/20181013003221/https://www.vanguardngr.com/2018/10/breaking-atiku-picks-peter-obi-as-running-mate/amp/ | archive-date=2018-10-13 | url-status=live | access-date=2022-07-15}}</ref>
 
'''Idibo gbogbogbo odun 2023'''
 
Ni 24 March 2022, Peter Obi kede ète rè láti díje fún ipò àárè lábé egbé oselu PDP sùgbón o padà ya si egbé oselu Labour Party(LP), labe egbé oselu náà ni o ti ún díje fún ipò àárè Nàìjíríà lowolowo.ref name="Ugwu 2022">{{cite web | last=Ugwu | first=Chinagorom | title=2023: Peter Obi declares for president, vows to create jobs, secure Nigeria | website=Premium Times Nigeria - Premium Times - Nigeria's leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria | date=2022-03-24 | url=https://www.premiumtimesng.com/regional/ssouth-east/519426-2023-peter-obi-declares-for-president-vows-to-create-jobs-secure-nigeria.html | access-date=2022-07-15}}</ref>
==Igbesi ayé rè==
Obi fé Margaret Brown son Obi ní odun 1992, wón bí omo méjì, omokunrin kan àti omobinrin kan. Obi jé omo ìjo Catholic
 
==Àwon ìtókasí==
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Peter_Obi"