Peter Obi

Olóṣèlú

Peter Obi (19 July, 1961) je oloselu omo ile Naijiria, ohun si ni lati 2006 Gomina Ipinle Anambra. O je omo egbe oloselu APGA. Won diboyan Obi fun igba keji gege bi Gomina Ipinle Anambra ni idiboyan to waye ni 6 February, 2010[1], Obi pelu ibo 97,843 bori Chris Ngige (AC) to gba ibo 60,240, ati Charles Soludo (PDP), nipo keta to gba ibo 59,365.

Peter Obi
Governor of Anambra State
In office
17 March 2006 – 2 November 2006
AsíwájúChris Ngige
Arọ́pòVirginia Etiaba
Governor of Anambra State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
9 February 2007
AsíwájúVirginia Etiaba
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 July 1961


ItokasiÀtúnṣe