Plánẹ́tì
(Àtúnjúwe láti Pálánẹ́tì)
Pílánẹ́tì gẹ́gẹ́ bí i Ẹgbẹ́ìrẹ́pọ̀ ìmọ̀ Òfurufú Káàkiriayé (IAU) ṣe ṣè'tumọ̀ rẹ̀ jẹ́ ohun òkè-ọrùn tí ó ń yí ìrànwọ́ ká tàbí aloku ọ̀run tí tíwúwosí rẹ̀ jẹ́ kí ó rí róbótó, tí kò tóbi púpọ̀ láti yíyọ́ ìgbónáinúikùn (anthothermonuclear fusion) láàyè nínú rẹ̀, tí ó sì ti gba àwọn oríṣiríṣi ìdènà kúra cartele dé santata lọ́nà tí ó ń gbà kọjá.
Àwọn Pílánẹ́tì tí ó wà nínú Ètò Òòrùn
àtúnṣeGẹ́gẹ́ bí (IAU) ṣe sọ, pílánẹ́tì mẹ́jọ ni wọ́n wà nínú ètò òòrùn. Àwọn nìwọ̀nyìí bí wọ́n ṣe ń jìnnà sí Òòrùn:
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |