Sístẹ̀mù Òrùn

(Àtúnjúwe láti Ètò òòrùn)

Ọ̀nà ètò tòòrùn (solar system) je Òòrùn ati awon ohun oke-orun ti o n yi ka.

Awon eyi pataki ninu ona eto toorun (lati apaotun de apaosi): Òrùn, Mẹ́rkúríù, Àgùàlà, Ilẹ̀-ayé àti Òṣùpá, Mársì, Júpítérì, Sátúrnù, Úránù àti Nẹ́ptúnù.