Pópù Benedict 16k

(Àtúnjúwe láti Pópù Benedict XVI)

Pope Benedict XVI (Látìnì: Benedictus XVI; orúkọ abiso ni Joseph Aloisius Ratzinger; 16 April 1927 – 31 December 2022) jẹ́ adarí ìjọ Kátólíìkì àgbáyé àti olórí Orílẹ̀ Vatican city láàrin 19 April 2005 títí di ìgbà tí ó kọ̀wé fi ṣe silẹ ni 28 February 2013. A yan Benedict gẹ́gẹ́ bi poopu ní ìgbà tí poopu télèrí, Pope John Paul II fi àyẹ́ sílè. Nígbà tí Benedict kọ̀wé fi ipò sílè, ó ní "Pope emeritus" ni kí wọ́n ma pe oun,[1] orúkọ yìí sì ni wọ́ ń pèé títí di ìgbà tí ó fi ayé sílè ní ọdun 2022.

Benedict XVI
Papacy began19 April 2005
Papacy ended13 March 2013
PredecessorJohn Paul II
SuccessorFrancis
Personal details
Born16 Oṣù Kẹrin 1927 (1927-04-16) (ọmọ ọdún 97)
Marktl am Inn, Bavaria, Germany
NationalityGerman and Vaticanese
SignaturePópù Benedict 16k's signature
Other Popes named Benedict

A fi àmì òróró yàn gẹ́gẹ́ bí àlùfáà ní ọdun 1951 ní Bavaria, Benedict bẹ̀rẹ̀ si ún kàwé títí wọ́n fi mọ̀ọ́ bi onímò ẹ̀kọ́ Teologi. Ó di ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmò Teologi nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún kan lé lógbọ̀n(31) ní ọdun 1958.

Ikú rẹ̀

àtúnṣe

Benedict jẹ́ ọmọ ọdún marundinlogorun(95) nígbà tí ó fi ayé sílè.[2]

Àwọn Itokasi

àtúnṣe
  1. Petin, Edward (26 February 2013). "Benedict's New Name: Pope Emeritus, His Holiness Benedict XVI, Roman Pontiff Emeritus". Retrieved 23 June 2018. 
  2. Winfield, Nicole (2022-12-31). "Benedict XVI, pope who resigned to spend final years in quiet, dies at 95". PBS NewsHour. Retrieved 2022-12-31.