Patience Okon George Ig-Patience Okon George.ogg listen (tí wọ́n bí ní 25 November 1991) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje eré-sísá.[2] Ó kópa nínú ìdíje irinwó mítà ní 2015 World Championships in Athletics, ní ìlú Beijing, China[3] àti ní 2016 Rio Olympic Games. George ti gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ ní ẹ̀ẹ̀mejì ọ̀tọ̀tọ̀, nínú ìdíje African Championships fún irinwó mítà. Ó sì ti fìgbà mẹ́ta jáwé olúborí nínú ìdíje ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, fún irinwó mítà.[4]

Patience Okon George
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kọkànlá 1991 (1991-11-25) (ọmọ ọdún 33)
Cross River State, Nigeria
Height1.69 m[1]
Weight63 kg
Sport
Orílẹ̀-èdèNigeria
Erẹ́ìdárayáTrack and field
Event(s)400 metres
ClubCross River
Achievements and titles
Personal best(s)400 m 50.71 s (2015)

Ní ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 2014, ó sá eré àkósá fún ìdíje 4 × 400 m relay fún ẹgbẹ́ Nàìjíríà, ó sì gbé ipò kejì, ní Glasgow Commonwealth Games. Bákan náà ni ó kópa nínú ìdíje 4 × 100 m fún Nàìjíríà.[5]

Okon George gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ nínú ìdíje 2014 African Championships in Marrakesh, pẹ̀lú Sade Abugan àti Kabange Mupopo ti ìlú Zambia. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ oníwúrà fún gbígbé ipò kìíní nínú ìdíje 4 × 400 m pẹ̀lú Regina George, Ada Benjamin, àti Sade Abugan.[6]

Àwọn ìkópa rẹ̀ nínú ìdíje àgbáyé

àtúnṣe
Aṣojú fún   Nàìjíríà
2013 World Championships Moscow, Russia 4 × 100 m relay DQ
6th 4 × 400 m relay 3:27.57
2014 World Indoor Championships Sopot, Poland 5th 4 × 400 m relay 3:31.59
World Relays Nassau, Bahamas 7th 4 × 200 m relay 1:33.71
3rd 4 × 400 m relay 3:23.41
Commonwealth Games Glasgow, United Kingdom 4th (h) 4 × 100 m relay 44.13
2nd 4 × 400 m relay 3:24.71
African Championships Marrakech, Morocco 3rd 400 m 51.68
1st 4 × 400 m relay 3:28.87
Continental Cup Marrakech, Morocco 3rd 4 × 400 m relay 3:25.511
2015 World Relays Nassau, Bahamas 10th (h) 4 × 400 m relay 3:32.16
World Championships Beijing, China 9th (sf) 400 m 50.76
5th 4 × 400 m relay 3:25.11
African Games Brazzaville, Republic of the Congo 2nd 400 m 50.71
1st 4 × 400 m relay 3:27.12
2016 African Championships Durban, South Africa 3rd 400 m 52.33
2nd 4 × 400 m relay 3:29.94
Olympic Games Rio de Janeiro, Brazil 23rd (sf) 400 m 52.52
2017 World Relays Nassau, Bahamas 5th 4 × 200 m relay 1:33.08
7th 4 × 400 m relay 3:32.94
World Championships London, United Kingdom 21st (sf) 400 m 52.60
5th 4 × 400 m relay 3:26.72
2018 Commonwealth Games Gold Coast, Queensland, Australia 400 m DQ
2nd 4 × 400 m relay 3:25.29
African Championships Asaba, Nigeria 5th 400 m 52.34
3rd 4 × 400 m relay 3:31.17
2019 World Relays Yokohama, Japan 17th (h) 4 × 100 m relay 45.07
18th (h) 4 × 400 m relay 3:32.10
African Games Rabat, Morocco 5th 400 m 52.18
1st 4 × 400 m relay 3:30.32
World Championships Doha, Qatar 17th (sf) 400 m 51.89
15th (h) 4 × 400 m relay 3:35.90
2021 Olympic Games Tokyo, Japan 30th (h) 400 m 52.41
12th (h) 4 × 100 m relay 43.25
2022 African Championships Port Louis, Mauritius 5th 400 m 52.98
3rd 4 × 400 m relay 3:36.24
2023 World Championships Budapest, Hungary 4 × 400 m relay DQ
2024 African Games Accra, Ghana 1st 4 × 400 m relay 3:27.29

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Rio 2016 bio". Archived from the original on 25 November 2016. Retrieved 24 November 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Patience Okon George". IAAF. 24 August 2015. Retrieved 23 August 2015. 
  3. Heats results
  4. Eludini, Tunde (17 July 2017). "Ogunlewe, Okon win third national titles at 2017 All-Nigeria Championships –...". AthleticsAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 28 February 2019. 
  5. "Athletics, Women's 4x400 m relay final". CGF. 2 August 2015. Archived from the original on 29 April 2015. Retrieved 4 September 2015. 
  6. "Nigeria’s GOLDEN GIRLS win 4x400m Title as curtain falls on 2014 African Champs!". Making of Champions. 14 August 2014. Retrieved 4 September 2015.