Orílẹ̀-èdè Olómìnira Zambia (pípè /ˈsæmbiə/) jẹ́ Orílẹ̀-èdè tileyika kan ni Apaguusu Afrika. Awon Orílẹ̀-èdè tó súnmọ ni Orílẹ̀-èdè Olómìnira Toseluarailu ile Kongo ní àríwá , Tanzania ni ariwa-ilaorun, Malawi ni ilaorun, Mozambique, Zimbabwe, Botswana, ati Namibia ni guusu, ati Angola ni iwoorun. Oluilu re ni Lusaka, tó bùdó sí apá gúúsù-arin ibe.

Republic of Zambia
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"One Zambia, One Nation"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèStand and Sing of Zambia, Proud and Free
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Lusaka
15°25′S 28°17′E / 15.417°S 28.283°E / -15.417; 28.283
Èdè àlòṣiṣẹ́ Gẹ̀ẹ́sì
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ Nyanja, Bemba, Lunda, Tonga, Lozi, Luvale, Kaonde.
Orúkọ aráàlú Ará Zambia
Ìjọba Orile-ede olominira
 -  Ààrẹ Edgar Lungu
 -  Igbákejì Ààrẹ Inonge Wina
Ilominira latowo Iparapo Ileoba 
 -  Date 24 October 1964 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 752,618 km2 [1](39th)
290,587 sq mi 
 -  Omi (%) 1
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 12,935,000[2] (71st)
 -  2000 census 9,885,591[3] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 17.2/km2 (191st)
44.5/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $18.454 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,541[4] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $13.000 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,086[4] 
Gini (2002–03) 42.1 (medium
HDI (2007) 0.434 (low) (165th)
Owóníná Zambian kwacha (ZMK)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CAT (UTC+2)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ òsì
Àmìọ̀rọ̀ Internet .zm
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 260ItokasiÀtúnṣe

  1. United Nations Statistics Division. "Population by sex, rate of population increase, surface area and density" (PDF). Retrieved 2007-11-09. 
  2. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  3. Central Statistical Office, Government of Zambia. "Population size, growth and composition" (PDF). Retrieved 2007-11-09. 
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Zambia". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.