Patricia Olubunmi Foluke Etteh (tí a bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù kẹjọ 1953)[1] jé omo egbe ile igbimo asojú Naijiria fún ekun Ayedaade/isokan/irewole lati osu kefa odún 1999 titi di osu kewaa odun 2007. Ó jé omo egbe Alliance for Democracy(AD) kí o tó padà darapo egbé People's Democratic Party(PDP).[2]

Patricia Olubunmi Foluke Etteh
Speaker of the House of Representatives of Nigeria
In office
6 June 2007 – 30 October 2007
DeputyBabangida Nguroje
AsíwájúAminu Bello Masari
Arọ́pòDimeji Bankole
Aṣojú ìkọ̀ Ayedaade/Isokan/Irewole
In office
1999–2007
ConstituencyAyedaade/Isokan/Irewole
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kẹjọ 1953 (1953-08-17) (ọmọ ọdún 71)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAD, lẹyìn náà PDP
(Àwọn) olólùfẹ́Married
Àwọn ọmọTwo
ResidenceIsale Popo, Ikire
Alma materUniversity of Buckingham
ProfessionOnídìrí, agbejọ́rò àti olóṣèlú

Àárò ayé àti èkó rè

àtúnṣe

A bi Etteh ni 17 August 1953. O kose onidiri sugbon o pada tèsíwájú ninú èkó rè láti kékó Ofin ní yunifásitì ti Buckingham ni United Kingdom ní odun 2013, ósì padà wá sí Nàìjíríà fún ipe sisé ofin ní odun 2016. [3]

Òsèlú

àtúnṣe

Etteh un se asojú Ayedaade/Isokan/Irewole constituency ni ìpínlè Osun. O kókó wolé lábé egbe oselu Alliance for Democracy(AD) sùgbón o yí si egbe oselu People's Democratic Party(PDP) nígbà to fé lo sáà keji ní ipo. Ni odun 2007, a dibo yan sí ipò adari(speaker) ilé ìgbìmò asofin, oun ni obinrin akoko to kókó di irú ipò béè mú nínú isejoba Nàìjíríà.[4] Óun àti ígbákejì rè padà kowe fi ipò náà sílè léyìn tí afi èsùn jibiti kan wón.[2]

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "NIGERIAN TRIBUNE - News". tribune.com.ng. 2007-09-26. Archived from the original on 2007-09-26. Retrieved 2022-05-22.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. 2.0 2.1 "Patricia Etteh,Role Model,Hairdresser,Beauty Therapist and Politician, Speaker of the Nigerian House of Representatives and Entreprenuer, Prominent Nigerian, Nigeria Personality Profiles". Nigeriagalleria. 1953-08-17. Retrieved 2022-05-22.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Nigeriagalleria 1953" defined multiple times with different content
  3. "Former House of Reps Speaker, Patricia Etteh, among 4,225 new lawyers". Vanguard News. 2016-11-29. Retrieved 2022-05-22. 
  4. "News -- Mark, Etteh, emerge Senate President, Speaker". odili.net. 2007-10-25. Archived from the original on 2007-10-25. Retrieved 2022-05-27.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)<nowiki>