Patricia Wangechi Kihoro (ti a bini ojo kerin osu kini odun 1986)[2][3] je osere, olorin ati adari eto radio ti owa lati ilu Kenya. O di olokiki nitori pe o kopa ni ipele eketa titi Tusker Project Fameeleyi ti o de igbeyin idije na. Ni pa sise ere, akoko ere ti o kopa ninu re je ere Miss Nobody eleyi je ki o gba yiyan ninu ami eye Kalasha Awardsasiwaju osere ti odara julo ni odun 2012. Ninu jara tv o je okan ninu osere ti o pataki julo ninu Groove Theory fiimu olorin, osi kopa ninu Demigods, Changes, Rush ati Makutano Junction.[4] Gegebi osise redio oti sise pelu One FM ati Homeboyz FM.[5][6]

Patricia Kihoro
Ọjọ́ìbíPatricia Wangechi Kihoro
4 Oṣù Kínní 1986 (1986-01-04) (ọmọ ọdún 38)
Nairobi, Kenya
Orílẹ̀-èdèKenyan
Iṣẹ́
  • akorin
  • osere
  • osise radio
Ìgbà iṣẹ́2004–titi di isinyin
Websitepatriciakihoro.com
Musical career
Irú orin

Igbesi aye ibẹrẹ àtúnṣe

Won bi Kihoro ni osu kini odun 1986, osi dagba si Nairobi, olosi ile iko Shepherd Junior Primary School fun eko akobere, lehin na olosi Moi Girl's School, ni Nairobi. O lo si ile eko giga titi Moi Universitynibi ti oti keko science ati psychology. Ni ile eko giga ni oti lo dije ni Tusker Project Fame.[7]

Ise àtúnṣe

Odun 2009 si 2012 àtúnṣe

Ni osu keta odun 2009, Kihoro ko pa ninu ayewo fun awon ti o ma kopa ninu Tusker Project Fame. ni odun 2010 won lo ninu ere orin fun orin Just a Band ha-he ti o da lori akoni Makmende.[8] Ni odun 2011 o ko ipa Pet Nanjala ni jara Changes.[9]Ni odun 2011 kana otun kopa ninu ere Miss Nobody, eleyi ni o je ki won yan fun ami eye Kalasha ni odun 2011. Ni odun 2012, owa lara awon ti okopa ninu fiimu orin ti akori re je Groove Theory. O ko ipa Biscuit, ololufe Zamm ninu ere ti oda lori igbesiaye awon omo ile eko Victoria University.[10]

Odun 2013 si 2014 àtúnṣe

Ni odun 2013 o ko pa ninu ereori telifisonu The Fattening Room[11]eleyi ni oje ki ohun ati awon alajosise se awokose asa ti awon eyan Efik ni apa guusu orile ede Nàìjíríà.[12] ni odun 2014 oko ipa Nana ninu jara Rush.[13]O se ere pelu Janet Mbugua, Wendy Kimani, Wendy Sankale and Maryanne Nundo.[14]

Odun 2015 titi di akokoyi àtúnṣe

Ni odun 2015, o ko ipa omo Maqbul Mohammed ninu jara Makutano Junction. Ni odun 2018 Kihoro ko ipa Josephine, iyawo titun si ikan ninu awon akopa iwaju titi fiimu Rafiki

Aworan iwoye àtúnṣe

Odun Nikan (awọn) Oludari Awo-orin Ref (awọn)
2011 "Nakupenda" rowspan=2 style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | TBA
Ọdun 2013 "Loving Wrong" (Calvo Mistari ti o ṣe afihan Patricia Kihoro) Edu G

Asayan ere àtúnṣe

Awọn fiimu ati tẹlifisiọnu àtúnṣe

Odun Akole Ipa Akiyesi
2009 Tusker Project Fame Ara e Odije pari
2011 Miss Nobody Juliette fiimu kukuru
2011 Changes Petronilla Nanjala
2011–13 Demigods Mona
2012 Mali Ara e ere ipele kan
2012 Out of Africa – A Safari Through Magical Kenya Ara e
2012–14 Groove Theory Biscuit
2013 Homecoming Alina Fiimu kukuru
2013 Life in a Single Lane Ara e
The Fattening Room Ara e
2014 There is Nothing to Do in Nairobi Patience Omondi Fiimu kukuru
2014 Rush Nana
2015–present Makutano Junction – Mabuki Jara
2018 Thomas and Friends Big World! Big Adventures! Nia (ohun akorin) Fiimu
2018 Discoonnect[15] Judy Ere ife
2018 Rafiki Josephine Film
Odun Ẹgbẹ Ẹka aami ẹbun Iṣẹ ti a yan Esi Ref (awọn)
2012 Kalasha Awards Oṣere Aṣere ti o dara julọ ninu Fiimu kan style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé

Awon itokasi àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Reverbnation: Patricia Kihoro". Reverbnation. Retrieved 1 February 2015. 
  2. "S3xy Homeboyz Radio presenter Patricia Kihoro reveals her age and leaves many surprised!". Mashada. Retrieved 1 February 2016. 
  3. "Patricia Wangechi Kihoro profile". World of Big Brother. Archived from the original on 1 April 2019. Retrieved 1 February 2016. 
  4. "Patricia Kihoro". Talent East Africa. Retrieved 5 February 2016. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. Chrysanthus Ikeh. "Patricia Kihoro to host shows with Homeboyz Radio 103.5". The Net. Retrieved 5 February 2016. 
  6. "Patricia Kihoro Lands New Radio Job". Nairobi Wire. Retrieved 5 February 2016. 
  7. "Patricia Kihoro-Rising to the top of Kenyan showbiz industry". SDE. 23 September 2015. Archived from the original on 25 July 2018. Retrieved 3 February 2016. 
  8. Vinograd, Cassandra (March 24, 2010). "Kenya Launches Country's First Viral Music Video". the wall street journal. https://blogs.wsj.com/speakeasy/2010/03/24/kenya-launches-countrys-first-viral-music-video/. 
  9. "HOT: Patricia Kihoro". Kenya Buzz. Archived from the original on 12 July 2016. Retrieved 3 February 2016. 
  10. "KENYA'S 1ST MUSICAL TV DRAMA SERIES- THE GROOVE THEORY". Actors.co.ke. 4 December 2013. Retrieved 3 February 2016. 
  11. Lasisi, Oluwafunke (28 April 2013). "EbonyLife Brings Six African Ladies to The Fattening Room". This Day Live. Retrieved 5 February 2016. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  12. "Fattening Room". Ebony Life TV. Archived from the original on 18 November 2021. Retrieved 5 February 2016. 
  13. "Rush; Kenyas version of sex and city". In The Loop. Retrieved 5 February 2016. 
  14. Baba Ghafla (18 April 2012). "Rush: New TV series packed with celebs". Ghafla!. Retrieved 5 February 2016. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  15. https://www.imdb.com/title/tt8413566

Awọn ọna asopọ ita àtúnṣe