Patrick Asadu (ẹni tí a bí ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1964) jẹ́ olóṣèlú àti onímọ̀ ìṣègùn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Patrick jẹ́ ọmọ ìlú Ovoko ní ìjọba ìbílẹ̀ Igbo-eze South, Ìpínlẹ̀ Enugu, òun sì ni aṣojú ìwọ Nsukka/Igbo-eze south ní Ilé ìgbìmọ̀ aṣojú Nàìjíríà. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ Honourable Commissioner Ìpínlẹ̀ Enugu rí, a yàn án sípò náà lẹ́yìn ìgbà tí ó dara pọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú People Democratic Party (PDP).[1]

Patrick Asadu
Nigerian Lawmaker for Enugu State
AsíwájúHon Charles Ugwu
ConstituencyNsukka/Igbo-eze South
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Kẹjọ 1964 (1964-08-23) (ọmọ ọdún 60)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)
ProfessionMedical practitioner, politician

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Asadu sí inú ìdílé Pa David Ezenwa Asadu àti Mary Oriefi Asadu (nee Eze-Okwechi). Ó kàwé ní ilé ìwé Boy's Secondary School, Woko, ó sì gba ìwé ẹ̀rí West African Examination Council (WAEC) ní ọdún 1982. Asadu ka nípa ìmò ìsègùn òyìnbó (medicine and surgery) ní Yunifásítì ilẹ̀ Nàìjíríà (UNN), Nsukka ó sì kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìsègùn òyìnbó (MBBS) ní ọdún 1988. Ó tún gba àmì ẹyẹ Master's of Public Health ní Yunifásítì Nàíjíría, Nsukka. Asadu ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí oníṣègùn òyìnbó ní ètò ìjọba àti ti a ládánì.[2]

Àwọn ipò ìjọba tí ó ti dì mú

àtúnṣe

Asadu has held several political offices, which include:

  • Hon. Commissioner for Sciecnce & Technology, Enugu State – 2001[3]
  • Hon. Commissioner for Land and Housing, Enugu State 2000–2001
  • Hon. Commissioner for Health Enugu state 2001–2002
  • Chairman Transition Committee, Igbo-Eze South LGA 2002–2003
  • Hon. Commissioner for Agriculture Enugu State 2003–2005
  • Hon. Commissioner for Environment Enugu State 2005–2006

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Hon. Patrick Asadu biography, net worth, age, family, contact & picture". www.manpower.com.ng. Retrieved 2022-09-23. 
  2. "Board of Directors – First Guarantee Pension" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-09-23. 
  3. "National Assembly | Federal Republic of Nigeria". nass.gov.ng. Retrieved 2022-09-23.