Paul Laurence Dunbar
Paul Laurence Dunbar (June 27, 1872 – February 9, 1906) je was an akoewi, asaroso, ati olukowe-ere omo Afrika Amerika to gbe ni opin orundun 19k ati ibere orundun 20k. O ko opo awon iwe to gbajumo re pelu ede-enu Alawodudu, eyi so di olukowe omo Afrika Amerika akoko to gbajumo kakiri orile-ede Amerika nigbana.
Paul Laurence Dunbar | |
---|---|
Dunbar circa 1890 | |
Ọjọ́ìbí | Dayton, Ohio, United States | Oṣù Kẹfà 27, 1872
Aláìsí | February 9, 1906 Dayton, Ohio | (ọmọ ọdún 33)
Cause of death | Tuberculosis |
Resting place | Woodland Cemetery Dayton, Ohio |
Orílẹ̀-èdè | American |
Iṣẹ́ | Poet |
Olólùfẹ́ | Alice Dunbar |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |