Pelu Awofeso
Pelu Awofeso jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-edè Nàìjíríà, ó jẹ́ ọ̀ǹkọ̀wé nípa ìrìn-àjò àti àṣà, tó ń gbé ìlú Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jáwẹ́ olúborí nínú ìdíje ti CNN/Multichoice ní Africa fún àmì-ẹ̀yẹ ti ẹ̀ka àwọn oníròyìn nípa ìrìn-àjò. Ní ọ̀pọ̀ ìgbà ní à ń ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gé bíi "aṣáájú òǹkọ̀wé nípa ìrìn-àjò" [1] Ó tún jẹ́ òǹkọ̀wé tí a ṣatẹ̀jáde ìwé rẹ̀.[2]
Pelu Awofeso | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Journalist, travel-writer, tour guide |
Gbajúmọ̀ fún | Tour guiding, travel writing |
Awards | CNN/Multichoice African Journalists Award |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Pelu Awofeso: Nigeria’s foremost travel writer | MyWeku Tastes". MyWeku Tastes. 10 April 2016. Archived from the original on 6 November 2017. https://web.archive.org/web/20171106103928/http://mywekutastes.com/pelu-awofeso-nigerias-foremost-travel-writer/.
- ↑ "Ajimobi, Tinubu urge journalists to be fearless". The Punch. Archived from the original on 2015-06-15. Retrieved 2015-06-13. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)