Philip Bailey jẹ́ ọmọ Ọkùnrin kan pàtó èyí tí a bí ni ọjọ́ kẹjọ oṣù kàrún-un ọdún 1951 in ilẹ̀ Amẹ́ríkà.O jẹ R&B, o máa n ko orin ti ẹ̀mí o jẹ Olórin tí ó sí tún máa nkọ orin sílẹ̀

Philip Bailey
Bailey in 2000
Bailey in 2000
Background information
Orúkọ àbísọPhilip James Bailey
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kàrún 1951 (1951-05-08) (ọmọ ọdún 73)
Denver, Colorado, U.S.
Irú orin
Occupation(s)
  • Olórin
  • oǹkọ̀wé orin
  • ọ̀kọrin
Instruments
  • Vocals
  • percussion
  • kalimba
Years active1970–present
Labels
Associated acts
Websitewww.philipbailey.com

.Ti a sì tún mọ sí tún mọ sí ẹni tí o máa n síwájú orin ni kikọ lati inu ohun ẹnu.pelu àwọn ọmọ][ group founder Maurice white. ti ayé iji ati ína .pu Gbogbo akitiyan re o ti gba awoodu méje eyi tí o je awoodu n la .

Bailey ti tẹ onírúurú awọn orin jáde. Ni odun 1984 ni o gba awoodu ti Chinese Wall, gégé bí eni ti o korin dára jù ní ìdíje orin náà. Ni oṣù kàrún-un ọdún 2008,Bailey tun gba ipò pataki kan ti awọn elede gẹẹsi n pe ni Honrary Doctorate] ti orin kíkọ láti ọdọ àwọn Berklee College of Music.


igbe ayé rẹ àti àwọn iṣẹ rẹ

ìbẹrẹ pẹpẹ̀ ayé Bailey

Bailey je ọmọ ti a bí ti a sì to dàgbà ni Denver, ti Colorado. O lo sí Ile iwe girama ti Denver ìla oòrùn. O tun wa lọ sí ilé iwe gíga fasiti ti Metropolitan ti Denver àti fasity Colorado leyin ti o ti lọ sí ilé iwe gíga fasiti Metropolitan.

Bailey tún wà lára àwọn ẹgbẹ ti R ati B ti ibile èyí tí wọn pè ní Ọrẹ ati ìfẹ.[7] [8].

Lára àwọn ìbẹrẹ pẹpẹ̀ ayé orin Bailey ni o ti korin pẹlu awọn Olórin jaasi bíi aMiors Davis, John Coltrane àti Max Roach, awọn Olohun Motown ninu orin Stevie Wonder pàtó lára àwọn Olorin obinrin tí Bailey tún ti ba se awon nnkan iṣẹ rẹ ni Sarah Vanghan àti Dionne Warwick náà wá.[9]

]










Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe