Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica
Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica (Èdè Látìnì fún Àwọn Ìpilẹ̀sẹ̀ Matimátíìkì fún Imọ̀-òye Adánidá, Mathematical Principles of Natural Philosophy ní èdè Gẹ̀ẹ́sì),[1] tí wọ́n tún tọ́ka sí bíi Principia ( /prɪnˈsɪpiə,_prɪnˈkɪpiə/ prinkípíà), ni ìwé apá mẹ́ta tí Isaac Newton kọ ní èdè Látìnì, tí wọ́n kọ́kọ́ tẹ̀jáde ní 5 July ọdún 1687.[2] Lẹ́yìn tí Newton ṣe àtúnṣe sí àtẹ̀jáde àkọ́kọ́ ìwé yìí,[3] ó tún tún tẹ̀ jáde ní ọdún 1713 àti ọdún 1726. Principia ṣe àkọsílẹ̀ àwọn òfin ìmúrìn Newton, tí wón jẹ́ ìpìlẹ̀ ìṣiṣẹ́-ẹ̀rọ ògbólògbó; òfin ìfàmọ́ra gbogbo únkan Newton; àtí ìwájáde àwọn òfin ìmúrìn plánẹ́tì Kepler (tí Kepler kọ́kọ́ fi first obtained ọgbọ́n ìrírí wá jáde).
Title page of Principia, first edition (1687) | |
Olùkọ̀wé | Sir Isaac Newton |
---|---|
Àkọlé àkọ́kọ́ | Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica |
Language | New Latin |
Publication date | 1687 (1st ed.) |
Published in English | 1728 |
LC Class | QA803 .A53 |
Awọn ẹda
àtúnṣe- Philosophiae naturalis principia mathematica, auctore Is. Newton, Londini, iussu Societatis Regiae ac typis Josephi Streater, anno MDCLXXXVII (akọkọ)
- Philosophiae naturalis principia mathematica, auctore Isaaco Newtono, Cantabrigiae, MDCCXIII (keji)
- Philosophiae naturalis principia mathematica, auctore Isaaco Newtono, Editio tertia aucta & emendata, Londini, apud Guil. & Ioh. Innys, MDCCXXVI (ni ipari)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The Mathematical Principles of Natural Philosophy", Encyclopædia Britannica, London
- ↑ Andrew Motte
- ↑ Newton, Isaac. "Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica (Newton ká tikalararẹ àtúnse 1st)".