Phylicia Rashad

(Àtúnjúwe láti Phylicia Rashād)

Phylicia Rashād (oruko abiso Phylicia Ayers-Allen; June 19, 1948) je osere ati akorin ara American to gba Ebun Tony, o gbajumo fun ere re gegebi Clair Huxtable ninu ere telifisan The Cosby Show.

Phylicia Rashād
At the 2007 Red Dress Collection for The Heart Truth Foundation
Ọjọ́ìbíPhylicia Ayers-Allen
19 Oṣù Kẹfà 1948 (1948-06-19) (ọmọ ọdún 76)
Houston, Texas, USA
Iléẹ̀kọ́ gígaHoward University
Iṣẹ́Akorin, osere, oludari ere ori-itage
Ìgbà iṣẹ́1972–d'oni
Olólùfẹ́
Àwọn ọmọ2, ikan ni Condola Rashād
Àwọn olùbátanDebbie Allen (aburo)