Portuguese Angola
Portuguese Angola jẹ́ o Angola nígbà tí wọ́n wà lábẹ́ ìjọba Portuguese ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn Áfríkà. Orúkọ ko rẹ̀ títí di ọdún 1951 ni Portuguese West Africa (tàbí State of West Africa).
|
Ní ṣẹ́ntúrì ogún ni Ìjàdù fún Áfríkà ni àwọn alágbara ní Europe tó kó gbogbo ìlú náà lẹ́rú.
Ìtàn
àtúnṣePortuguese jọba lórí Angola láàrin ìgbà tí Diogo Cão jọba ní ọdún 1484[3] títí ti osù kọkànlá ọdún 1975. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ǹkan ni ó ṣẹlẹ̀ láàrin ọgọ́rùn-ún márùn-ún ọdún yìí.
Ìgbà tí wọ́n ko wọn lẹ́rú
àtúnṣeAngola ò tí sí nígbà tí Diogo Cão àti àwọn tó kù rẹ̀ dé Ìjọba Kongo ní ṣẹ́ńtúrì kẹ̀ẹ́dógún. Ibi tí Angola wà lọ́wọ́ lọ́wọ́ jẹ́ ibi tí oríṣiríṣi àwọn ẹ̀yà àti ènìyàn wà nígbà náà. Ète àwọn ará Portugal nígbà náà ni láti kó ẹrú. Wọ́n sì ní ìbásepọ̀ tó da pẹ̀lú àwọn adarí àti òtòkùlú ìjọba Kongo, wọ́n fi ẹ̀sìn Kristẹ́nì lọ̀ wọ́n, wọ́n sì kọ́ wọn ní èdè Portuguese, wọ́n tún jé kí wọn jẹ àwọn ànfàní ọkọ òwò ẹrú tí wọ́n ń ṣe.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ James, Martin W. (2004). Historical Dictionary of Angola. Scarecrow Press. p. 140. ISBN 9780810865600. https://books.google.com/books?id=JTSoqGzOPXsC&q=angola+state+religion&pg=PA140.
- ↑ as Captain-Governor
- ↑ Chisholm 1911.