Princess Brun Njua
Princess Brun Njua (tí wọ́n bí ní 26 January 1986) jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Cameroon tó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ[1]. Ó padà wá sí gbàgede ní ọdún 2014 lẹ́yìn tó farahàn nínú fíìmù àgbéléwò tí orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, ìyẹn ITV TV Judge Rinder. Òun ni olùgba àmì-ẹ̀yẹ BEFFTA[2], èyí tó gbà ní ọdún 2016.
Princess Brun Njua | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kínní 1986 Kom, Northwest Region, Cameroon |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Cameroonian |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeBrun Njua (tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí Brunhilda Njua) ni wọ́n bí ní 26 January 1986[3] sí ìlú Kom, èyí tó wá̀ ní apá Àríwá ilẹ̀ Cameroon. Brun pàdánù àwọn òbí rẹ̀ méjèèjì sínú ijàm̀bá ọkọ kan, nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́rìnlá. Láti ìgbà náà ló sì ti ń tiraka láti bọ́ ara rẹ̀.
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeNígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́tàlá (13), Brun bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa nínú eré ìtàgé ní ilé-ìjọsìn. Fìímù àgbéléwò àkọ́kọ́ rẹ̀ tó hàn lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ni ti ITV TV Judge Rinder.[4]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Fíìmù | Ojúṣe | Ọ̀rọ̀ |
---|---|---|---|
2014 | Judge Rinder (TV Show) | Herself | |
2014 | For the Love of Money (Film) | with Victoria Abraham, Collins Archie-Pearce, Kande Fatoumata & Fergurson Jack. | |
2015 | Gold Dust Ikenga (Film) | Doris | with Van Vicker, Stevie Maxwell-Smith & Malcolm Benson. |
2016 | Slave Dancer (Film) | Slave Dancer was written and co-produced by Brun Njua and features Tchidi Chikere. | |
2017 | Breach of Trust (Film) | Oler Array | |
2019 | Switch (Film) | Tandi | Switch is a movie by talented filmmaker Olumide Fadeyibi. |
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Fíìmù | Èsì |
---|---|---|---|---|
2015 | 5th U.K Nollywood & VoxAfrica | Special Recognition | Gold Dust Ikenga | Gbàá |
2015 | CAAUK Awards | Best Actress | Gold Dust Ikenga | Gbàá |
2016 | 2016 NRIDB Awards | Charity Ambassador | Gbàá | |
2016 | 2016 BEFFTA | Star Award | Gbàá |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ https://offtherecordblog.org/2018/09/17/interview-with-brun-njua/ Archived 2021-11-24 at the Wayback Machine. From an interview conducted with Miss Brun Njua back in September 2018
- ↑ http://www.beffta.com/news/ Brun Njua won a star Award in 2016
- ↑ "Princess Brun Njua: Facts You Need To Know About Nollywood Actress". allafrica. Retrieved 3 November 2015.
- ↑ "London Based Nollywood Filmmaker Taken To Court By A Nollywood Actress/Model". africandazzle. Retrieved 15 November 2015.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]