Van Vicker
Joseph van Vicker (tí wọ́n bí ní 1 August 1977),[1] tí wọ́n tún mọ̀ sí Van Vicker, jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana, ó sì tún jẹ́ olùdarí eré àti aṣèfẹ́-ọmọnìyàn. Òun ni olùdarí ilé-iṣẹ́ Sky + Orange production, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó ń ṣe fíìmù. Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ méjì, àkọ́kọ́ fún "Òṣèrékùnrin tó dára jù nínú eré" àti "Òṣèrékùnrin tó ń di gbajúmọ̀ bọ̀" ní Africa Movie Academy Awards, ní ọdún 2008.[2][3]
Joseph van Vicker | |
---|---|
Van Vicker in 2016 | |
Ọjọ́ìbí | Joseph van Vicker 1 Oṣù Kẹjọ 1977 Accra, Ghana |
Iléẹ̀kọ́ gíga | African University College of Communications |
Iṣẹ́ | Film and television actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2000–present |
Awards |
|
Website | vanvicker.org |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Vicker ní ìlú Accra, ní Ghana. Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ghana tó tan mọ́ ilẹ̀ Liberia[4], bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ará Netherland.[5][6][7] Bàbá rẹ̀ kú nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́fà.[6]
Vicker lọ sí ilé-ìwé Mfantsipim,[8] pẹ̀lú òṣèrékùnrin ẹgbẹ́ rẹ̀, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Majid Michel. Ó gboyè ẹ̀kọ́ ní African University College of Communications, ní ọdún 2021.[9]
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Olùgbà | Èsì |
---|---|---|---|---|
2008 | 4th Africa Movie Academy Awards | Best Actor in a Leading Role | The Return of Beyonce/Princess Tyra | Wọ́n pèé |
Best Upcoming Actor | Wọ́n pèé[2][3] | |||
2009 | Afro-Hollywood Award | Best Actor (African film category) | Gbàá[10][11] | |
2010 | 2010 Ghana Movie Awards | Best Actor Leading Role (Local Film) | Dna Test | Yàán |
2011 | 2011 Ghana Movie Awards | Best Actor Leading Role | Paparazzi | Yàán |
2011 | Pan African Film Festival | Africa Channel's Creative Achievement Award | Himself | Gbàá[12] |
2012 | Nafca | Best Comedy Movie | Joni Waka | Gbàá |
2013 | 2013 Ghana Movie Awards | Best Actor (Local Film) | Joni Waka | Gbàá[13] |
Pyprus Magazine Screen Actors Awards | Best International Actor | Gbàá | ||
2014 | 2014 Ghana Movie Awards | Favourite Actor | Yàán | |
2015 | Nafca | Best Actor in a Leading role (Diaspora film) | Heart Breaker's Revenge | Wọ́n pèé |
2016 | 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Actor Drama/Series | A long Night | Yàán |
2016 Nigeria Entertainment Awards | Best Actor Africa/Non Nigerian | Yàán | ||
KumaWood Awards | Best Collaboration | Broni W'awu | Gbàá |
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Fíìmù | Ojúṣe | Ọ̀rọ̀ |
---|---|---|---|
2004 | Divine Love | with Majid Michel & Jackie Appiah | |
2006 | Beyonce: The President's Daughter | Raj | with Nadia Buari & Jackie Appiah |
Darkness of Sorrow | CK (Charles) | with Nadia Buari | |
Mummy's Daughter | with Nadia Buari & Jackie Appiah & Okediji Alexandra | ||
The Return of Beyonce | Raj | with Nadia Buari & Jackie Appiah | |
2007 | American Boy | "Nelly" | with Nadia Buari |
I Hate Women | Rocky | with Jackie Appiah | |
Innocent Soul | |||
In the Eyes of My Husband | Leo | with Nadia Buari | |
Princess Tyra | Kay | with Jackie Appiah, Yvonne Nelson | |
Royal Battle | Lawrence | with Majid Michel & Jackie Appiah | |
Slave to Lust | with Nadia Buari, Ini Edo, Mike Ezuruonye & Olu Jacobs | ||
Wedlock of the Gods | |||
2008 | Broken Tears | Ben | with Genevieve Nnaji & Kate Henshaw |
Corporate Maid | Desmond | ||
Friday Night | |||
Jealous Princess | Sam | with Chika Ike & Oge Okoye | |
River of Tears | Ben | with Genevieve Nnaji & Kate Henshaw | |
Total Love | Nick[citation needed] | with Jackie Appiah | |
2009 | Twilight Sisters | Micky | with Oge Okoye |
Royal War | Uzodimma | with Ini Edo, Rachael Okonkwo | |
2009 | Beyond Conspiracy[14] | Michael | |
2010 | Discovered[14] | ||
2010 | Loyal Enemies[14] | ||
2010 | Kingdom in Flames[15] | ||
2011 | Paparazzi: Eye in the Dark | Rich | |
2013 | One Night In Vegas | Tony | with Jimmy Jean-Louis, Michael Blackson, Sarodj Bertin |
2014 | The Heart Breaker's Revenge | Dalyboy | with Dalyboy Belgason, Brittany Mayti, Sarodj Bertin |
2016 | Skinned | Robert/ Bobby | with LisaRaye McCoy, Jasmine Burke |
2017 | Cop's Enemy | Christopher "Shadow" Ifechi | |
Pending | Day After Death | with Wema Sepetu |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "birthday". Theafricandream.net. 25 July 2020. Retrieved 25 July 2020.
- ↑ 2.0 2.1 "Africa Movie Academy Awards' nominees take a bow in Josies". Archived from the original on 8 February 2010. Retrieved 23 October 2009. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 3.0 3.1 "AMAA Nominees and Winners 2008". Africa Movie Academy Award. Archived from the original on 5 April 2011. Retrieved 7 March 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigeria: Growing Up Without a Father Made Me Tough- Van Vicker". Allafrica.com. Retrieved 28 November 2021.
- ↑ Olatunji, Samuel (21 January 2010). "My life, my story, my wife— Van Vicker". The Daily Sun (Lagos, Nigeria). http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showpiece/2010/jan/31/showpiece-31-01-2010-001.htm.
- ↑ 6.0 6.1 "Van's Biography". Vanvicker.com. Archived from the original on 28 March 2009. Retrieved 7 March 2011.
- ↑ "Van Vicker (the well-known African actor) in Boston". Belmizikfm.com. Massachusetts, USA. 6 May 2009. Archived from the original on 27 February 2012. Retrieved 7 March 2011.
- ↑ "Van Vicker". .ghanacelebrities.com. Retrieved 22 February 2015.
- ↑ "Van Vicker finally graduates from university after 24 years". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-26. Retrieved 2021-07-27.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedsource1
- ↑ Akande, Victor (15 November 2010). "London agog for Afro Hollywood Award 2009". The Nation (Lagos, Nigeria). http://thenationonlineng.net/web2/articles/25360/1/London-agog-for-Afro-Hollywood-Award-2009/Page1.html.
- ↑ "Van Vicker To Receive Creative Award At The 20th Annual Pan African Film Festival", News Ghana, 1 February 2012.
- ↑ "Nadia Buari & Van Vicker Bag Best Actress and Actor at 2012 Ghana Movie Awards". twimovies. Archived from the original on 15 November 2021. Retrieved 30 August 2015.
- ↑ 14.0 14.1 14.2 "Van Vicker". Van Vicker (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 10 August 2016. Retrieved 23 April 2016.
- ↑ "Movies". Van Vicker (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 10 August 2016. Retrieved 23 April 2016.