Quett Ketumile Joni Masire, GCMG (ojoibi July 23, 1925 ni Kanye, Botswana) je oloselu ati Aare ikeji orile-ede Botswana lati 1980 de 1998, o je omo egbe oloselu Egbe Toseluarailu Botswana. Nigba to kosesile ni 1998, Festus Mogae to je Igbakeji Aare ropo re lati di Aare ile Botswana keta.

Quett Ketumile Joni Masire
2nd Aare ile Botswana
In office
July 13, 1980 – March 31, 1998
AsíwájúSeretse Khama
Arọ́pòFestus Mogae
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Keje 1925 (1925-07-23) (ọmọ ọdún 99)
Kanye, Botswana (nigbana bi Ileabo ti UK)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúEgbe Toseluarailu Botswana (BDP)