Seretse Khama, (1 July 1921 – 13 July 1980) je oloselu ara orile-ede Botswana ati Aare ile Botswana akoko ni odun 1966 titi di ojo to di alaisi ni ojoketala osu keje odun 1980.

Seretse Khama
Aare ile Botwana 1kọ
In office
30 September 1966 – 13 July 1980
Vice PresidentQuett Masire
AsíwájúSekgoma Khama, King (Kgosi) Sekgoma II (1923-1925)
Arọ́pòQuett Ketumile Joni Masire
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1921-07-01)1 Oṣù Keje 1921
Serowe
Aláìsí13 July 1980(1980-07-13) (ọmọ ọdún 59)
Gaborone
Ẹgbẹ́ olóṣèlúBotswana Democratic Party (BDP)
(Àwọn) olólùfẹ́Ruth Williams Khama



Itokasi àtúnṣe