Rafiatou Karimou
Rafiatou Karimou (2 May 1946 – 4 January 2018)[1] jẹ́ òṣèlú àti olùkọ́ ọmọ orílẹ̀ ède Benin. Karimou ni obìnrin àkọ́kọ́ láti di mínísítà ní orílẹ̀ ède Benin.[2][3][4]
Nípa ayé rẹ̀
àtúnṣeA bí Rafiatou Karimou ní ọdún 1946 ní Sakété, ní gúúsù ibi tí a mọ̀ sí Benin lóde òní. Ní ọdún 1975, òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí a yàn gẹ́gẹ́ bi olóyè àgbègbè àti ní ọdún 1989, ó di obìrin àkọ́kọ́ láti di mínísítà ni orílẹ̀ ède Benin nígbà tí àárẹ̀ orílẹ̀ èdè náà, Mathieu Kérékou yàn án sípò mínísítà fún ètò ìlera àdúgbò.[4]
Ó di ipò yìí mú di ọdún 1990. A tún yàn án láti láti dípò mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ Prámárì àti Sẹ́kọ́ndírì, ó sì di ipò náà mú láti ọdún 2003 títí di 2006.[5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Décès de Karim Rafiatou hier à Paris La première femme ministre du Bénin n'est plus". Retrieved 1 May 2018.
- ↑ "Le FED de Karimou Rafiatou se prononce: Actualité politique au Bénin | Jolome News - La pluralité de l'information". bj.jolome.com (in Èdè Faransé). Retrieved 2017-11-07.
- ↑ rédaction, La. "La nouvelle carte politique de Sakété" (in fr-FR). La Nouvelle Tribune. Archived from the original on 2019-05-24. https://web.archive.org/web/20190524045637/https://lanouvelletribune.info/archives/benin/politique/5785-la-nouvelle-carte-politique-de-sakete.
- ↑ 4.0 4.1 Attanasso, Marie-Odile (2013) (in fr). Femmes et pouvoir politique au Benin des origines dahoméennes a nos jours. Friedrich-Ebert-Stiftung. ISBN 9789991914114. https://books.google.com/books?id=1bf0oAEACAAJ&q=9789991914114.
- ↑ Houngnikpo, Mathurin C.; Decalo, Samuel (2013) (in en). Historical Dictionary of Benin. Rowman & Littlefield. ISBN 9780810871717. https://books.google.com/books?id=0yGPTsRubWEC.
- ↑ Marie-Odile, Attanasso C. (2012) (in fr). Femmes et pouvoir politique au Bénin : Des origines dahoméennes à nos jours. Fondation Friedrich Ebert. http://library.fes.de/pdf-files/bueros/benin/10194.pdf.