Rafiq Ahmad Pampori
Rafiq Ahmad Pampori (born 13 February 1956) jẹ́ onímọ̀ Mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè India, onímọ̀ àti òǹkọ̀wé, tó ṣe ìdásílẹ̀ Darul Uloom Ilahiya, tó jẹ́ ilé-ìwé Islam ní ìlú Srinagar.
Rafiq Ahmad Pampori | |
---|---|
Rector of Darul Uloom Ilahiya, Srinagar | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1992 | |
Asíwájú | "post established" |
Principal of Government Medical College, Srinagar | |
In office 1 October 2012 – 19 December 2015 | |
Asíwájú | Qazi Masood |
Arọ́pò | Kaisar Ahmad |
Àdàkọ:Infobox religious biography |
Ahmad kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Sri Pratap College àti Government Medical College, Srinagar. Òun ni rector Darul Uloom Ilahiya, ní Srinagar àti olùdarí Illahiya Dialysis ní Soura. Ó fígbá kan jẹ́ ọ̀gá ilé-ìwé Government Medical College. Ó ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé bíi: Aijazul Qur'ān àti Ra'fatul Baari, ìwé alápá márùn-ún Sahih Bukhari.
Ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Rafiq Ahmad Pampori ní ọjọ́ 13 oṣù February, ọdún 1956 ní Safa Kadal, Srinagar. Ó lọ sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Karan Nagar, ó sì parí ẹ̀kọ́ girama ní Sri Pratap College, ní ọdún 1974.[1] Ó kẹ́ẹ̀kọ́ nípa ìṣègùn, ní Government Medical College, Srinagar, níbi tí ó ti gboyè Bachelor of Medicine and Surgery (MBBS) ní ọdún 1979, ó sì tún tẹ̀síwájú láti gboye Master of Surgery nínú ẹ̀kọ́ Otorhinolaryngology (ENT) láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà, ní ọdún 1983.[2] Ó ṣe Neurotology fellowship ní All India Institute of Medical Sciences ní New Delhi.[1] Ó gba àǹfààní Muhammad Masihullah Khan nínú Sufism.[3]
Ní ọdún 1983, wọ́n yan Ahmad sípò alákòóso ìforúkọsílẹ̀ ti Government Medical College, ní Srinagar.[4] Ní ọdún 1990, wọ́n yàn án sípò olùkọ́ lábé ẹ̀ka ENT tí ilé-ẹ̀kọ́ náà, tí ó sì padà di olórí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n.[4] Wọ́n yàn án sípò olùdarí ilé-ìwé náà, ní 1 oṣù October, ọdún 2012.[5][6] Ó gba ìsinmi lẹ́nu iṣẹ́ ní oṣù December, ọdún 2015, tó sì bèrè fún ìfẹ̀hìntì, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ọjọ́ 1 oṣù February, ọdún 2018 ló yẹ kí ó fẹ̀yìntì.[4][7] Wọ́n fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé Lal Singh Chaudhary, tó jẹ́ olóṣèlú BJP kàn án nípá láti fẹ̀hìntí láìtọ́jọ́.[8]
Ahmad ṣe àyọkúrò ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ fún ètò ìfẹ̀hìntì rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Mufti Mohammad Sayeed ṣe béèrè fun.[9] Àmọ́, Lal Singh ti yan Kaiser Ahmad gẹ́gẹ́ bí i olùdarí ilé-ìwé náà, ní ọjọ́ 19 oṣù December, ọdún 2015, tó kọ̀ láti fi ipò náà sílẹ̀.[10][11] Wọ́n ri bí i "ìfìgagbágba àti ogun láàrin PDP v/s BJP" láti ọwọ́ Omar Abdullah.[10]
Àwọn iṣẹ́ àtẹ̀jáde rẹ̀
àtúnṣeAhmad ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé bíi: Aijazul Qur'ān, Instrument For Understanding Qur'ān, Ra'fatul Baari (a five-volume commentary on Sahih Bukhari) àti The Need for Divine Guidance.[2] Àwọn iṣẹ́ àtẹ̀jáde rẹ̀ mìíràn ni:
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 MANZOOR-UL-HASSSAN (14 March 2015). "Dr Rafiq Pampori is new GMC Principal". Greater Kashmir. https://www.greaterkashmir.com/more/dr-rafiq-pampori-is-new-gmc-principal.
- ↑ 2.0 2.1 Khan & Ansar 2018, p. 78.
- ↑ Trāli & al-Azam 2015, pp. 428–432.
- ↑ 4.0 4.1 4.2 MANZOOR-UL-HASSSAN (14 March 2015). "Dr Rafiq Pampori is new GMC Principal". Greater Kashmir. https://www.greaterkashmir.com/more/dr-rafiq-pampori-is-new-gmc-principal.
- ↑ "Transfers and postings in J&K administration". Scoop News. http://scoopnews.in/det.aspx?q=33751.
- ↑ Sheikh Junaid (19 December 2015). "Health minister 'pushed' Kashmir medical college principal to resign". Kashmir Dispatch. Archived from the original on 9 July 2021. https://web.archive.org/web/20210709185300/https://kashmirdispatch.com/2015/12/19/health-minister-pushed-kashmir-medical-college-principal-to-resign/2644/.
- ↑ "HC issues notice to C/S Health". Daily Excelsior. 5 February 2016. https://www.dailyexcelsior.com/hc-issues-notice-to-cs-health/.
- ↑ VIVEK SHARMA (22 December 2015). "On CM's request, Dr Pampori withdraws retirement plea; joins". State Times. https://news.statetimes.in/132787-2/.
- ↑ VIVEK SHARMA (22 December 2015). "On CM's request, Dr Pampori withdraws retirement plea; joins". State Times. https://news.statetimes.in/132787-2/.
- ↑ 10.0 10.1 "PDP-BJP coalition making mockery of governance: Omar Abdullah". India Times. 23 December 2015. https://economictimes.indiatimes.com/news/politics-and-nation/pdp-bjp-coalition-making-mockery-of-governance-omar-abdullah/articleshow/50297530.cms?from=mdr.
- ↑ "Dr Javed Chowdhary vs State Of J&K; And Others on 27 October, 2017". indiankanoon.org. Archived from the original on 9 July 2021. Retrieved 4 July 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Maqbool, Mohammad; Maqbool, Suhail (31 August 2013). Textbook of Ear, Nose and Throat Diseases. ISBN 9789350904954. https://books.google.com/books?id=oTgIAQAAQBAJ&q=Rafiq+Ahmad+Pampori&pg=PR15. Retrieved 4 July 2021.
- ↑ Pampori, Rafiq Ahmad; Ahmad, Asif; Ahmad, Manzoor (January 2002). "Primary tumor of the facial nerve: Diagnosis and management". Indian Journal of Otolaryngology and Head and Neck Surgery 54 (1): 54–56. doi:10.1007/BF02911009. PMC 3450701. PMID 23119855. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3450701.
- ↑ Ahmad, Rauf; Pampori, Rafiq Ahmad; Wani, Asef Ahmad; Qazi, Sajjad Majid; Ahad, Sheikh Abdul (2000). "Transcervical foreign body". The Journal of Laryngology & Otology 114 (6): 471–472. doi:10.1258/0022215001905896. PMID 10962687. https://www.cambridge.org/core/journals/journal-of-laryngology-and-otology/article/abs/transcervical-foreign-body/9F4DB8C6FABD2A17ACB9EB6341F2C5DF.
Bibliography
àtúnṣe- Trāli, Nisar Aḥmad Bhat; al-Azam, Yūsuf (November 2015). "Darul Uloom Ilahiya" (in ur). Ā'īna-e-Madāris Jammu wa Kashmīr. 2. Srinagar: Afaq Printers. pp. 428–432.
- Khan, Muhammad Tayyab; Ansar, Asma (2018). "رفیق احمد پامپوری کا مطالعۂ قرآن: تجزیاتی مطالعہ". Journal of Ma'arif-e-Islami (Islamabad: Allama Iqbal Open University) 17 (1): 77–92. https://mei.aiou.edu.pk/?p=541. Retrieved 4 July 2021.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]