Ram Narayan (Híndì: राम नारायण; IAST: Rām Nārāyaṇ, IPA: [ˈraːm naːˈraːjn]; 25 December 1927 -9 November 2024), nigba miran ti won unpe ni Pandit, je olorin ara India to mu irinse orin sarangi gbajumo bi irinse orin agbo adalu ninu orin ogbologbo Hindu to si gbajumo kariaye bi onilu sarangi.

Ram Narayan
An old man sits cross-legged on a platform and plays a bowed instrument.
Narayan in Delhi in October 2010
Background information
Irú orinHindustani classical music
Instrumentssarangi
Years active1944–2013
Associated actsAbdul Wahid Khan, Brij Narayan, Chatur Lal, Suresh Talwalkar
Websiteramnarayansarangi.com

Narayan je bibi ni Udaipur o si ko lati ta sarangi lati igba kekere.