Rama Brew
Òṣèrébìnrin ilẹ̀ Ghana
Rama Brew jẹ́ òṣèrébìnrin ti ilẹ̀ Ghana àti olóòtú ètò lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ olórin.[1][2][3]
Rama Brew | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Iṣẹ́ | Actress, television personality and jazz musician |
Ìgbà iṣẹ́ | 1972–present |
Gbajúmọ̀ fún | Avenue A, Villa Kakalika, Farewell to Dope, Ultimate Paradise |
Àwọn ọmọ | Michelle Attoh |
Parent(s) | Michelle Attoh |
Ìtàn lórí ìbẹẹrẹ ayé Rama Brew
àtúnṣeRama ti ni lọ́kàn láti di oníjó láti ìgbà èwe rẹ̀, àmọ́ bàbá rẹ̀ kò gbà. Lẹ́yìn náà ni àbúrò bàbá rẹ̀ tó ń ṣiṣẹ́ ní Ghana Broadcasting Corporation(GBC) mú wọ iṣẹ́ lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán.[4]
Siwaju si
Rama ni omobirin kan ti oruko re n je Michelle Attoh ti oun naa si je oserebirin.
Awon itokasi
àtúnṣe- ↑ Ofori, Oral. "Rama Brew Tells Youth To Be Wary Of Showbiz, Also Asks Actors' Guild To Protect Artistes". Modern Ghana. Retrieved 31 August 2017.
- ↑ Yaob. "Mother of Ghollywood- Rama Brew". ModernGhana. Retrieved 4 September 2017.
- ↑ "How hockey curtailed Rama Brew's sporting career". GhanaWeb. Retrieved 4 September 2017.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Ofori, Oral. "Rama Brew Tells Youth To Be Wary Of Showbiz, Also Asks Actors' Guild To Protect Artistes". ModernGhana. Retrieved 4 September 2017.