Razia Sultan (Sinimá àgbéléwò)

Àdàkọ:Notability }}

Àdàkọ:Use Indian English

Razia Sultan
Fáìlì:Razia Sultan serial poster.jpg
Promotional image for Razia Sultan
GenreHistorical Drama
Created bySiddarth Kumar Tewary
Written byAnshuman Sinha
Surabhi Saral
Saba Mumtaz
Directed byMukesh kumar singh
Arif Ali Ansari
Hasnain Haiderabadwala
Manish Singh
Kamal Monga
Creative director(s)Prakriti Mukherjee
Amol Soorvey
Presented bySwastik Pictures
StarringSee Below
Country of originIndia
Original language(s)Hindi
No. of seasons1
No. of episodes170
Production
Producer(s)Siddarth Kumar Tewary
Gayatri Gill Tewary
Rahul Kumar Tewary
Production location(s)India
Editor(s)Paresh Shah
Ayan B Hashmi
Camera setupMulti-camera
Running timeApprox. 22 minutes
Production company(s)Swastik Pictures
Release
Original network&TV
Picture format576i (SDTV)
Original release2 Oṣù Kẹta 2015 (2015-03-02) – Oṣù Kẹ̀wá 23, 2015 (2015-10-23)
External links
Website

Razia Sultan jẹ́ Sinimá àgbéléwò orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán onípele tí wọ́n ṣe àfihàn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ ajé sí ọjọ́ Etì lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán &TV[1] láti ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 2015. Pankhuri Awasthy ni ó kópa olú ẹ̀dá ìtàn náà tí ó ń jẹ́ Razia Sultana. Eré-oníṣe náà dá lórí Razia Sultan (Sultan Razia), obìnrin kan ṣoṣo tí ó jọba ní Delhi Sultanate lórílẹ̀-èdè Indian. Ó dá lórí ọ̀dọ́mọbìnrin kan àti àwọn ìṣòro tí ó dojú kọ ọ́ ní ìgbésí-ayé rẹ̀. Ọ̀gbẹ́ni Shah Rukh Khan ni ó ṣe agbátẹrù eré náà gẹ́gẹ́ bí Sutradhar.[2] Orin tí Supriya Joshi kọ, tí àkọlé rẹ̀ ń Mere Maula ni wọ́n lò nínú sinimá náà.

Kókó ìtàn

àtúnṣe

Eré-oníṣe náà dá lórí ìtàn ìgbésí ayé ọmọbìnrin Razia Sultan. Bàbá rẹ̀, Sultan Iltutmish ni ó yàn án ní Àrẹ̀mọ tí ó jọba lẹ́yìn ara rẹ̀, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé ó ní àwọn ọmọkùnrin púpọ̀, ó gbàgbọ́ pé Razia tó gbangba sùn lọ́yẹ́, tí ó sìn ṣe é fọkàn tán ju àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ lọ. She was made the ruler by himself. Eré náà dá lórí akitiyan àti làálàá ojoojúmọ́ Razia gẹ́gẹ́ bí Ọbabìnrin Indian ní sẹ́ńtúrì kẹtàlá sẹ́yìn.

Àwọn ẹ̀dá-ìtàn

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe