Redeemer's University Nigeria

Ilé-ẹ̀kọ́ Redeemer's University jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ yunifasiti àdání tí wọ́n dá sílẹ̀ sí ìlú Ẹdẹ, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ní Nigeria. Wọ́n dá a sílẹ̀ lọ́dún 2005, ìjọ oníràpadà, the Redeemed Christian Church of God ó wà òpópónà ÌbàdànÒṣogbo.

Redeemer's University
RUN
Main entrance
MottoRunning with a Vision
Established2005; ọdún 20 sẹ́yìn (2005)
TypePrivate undergraduate & postgraduate
ChancellorTheophilus Danjuma
Vice-ChancellorShadrach Olufemi Akindele
LocationẸdẹ, Osun State, Nigeria
ColorsBlue, gold & white
Àdàkọ:Colour box Àdàkọ:Colour box Àdàkọ:Colour box
Websiterun.edu.ng/
Logo type of Redeemer's University.png