Regina ChukwuYo-Regina Chukwu.ogg gbọ́ jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùgbéjáde fíìmù ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3]

Regina Chukwu
Ọjọ́ìbíỌjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù kẹta[1][2]
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaPolytechnic ìpínlẹ̀ Èkó
Iṣẹ́Òṣèrébìnrin

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Regina Chukwu ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó lọ ilé-ìwé Alimosho Primary and Grammar School kí ó tó tẹ̀síwájú ní Polytechnic ìpínlẹ̀ Èkó.[4][5]

Àtòjọ àwọn fíìmù tí ó ti ṣeré

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Regina Chukwu celebrates birthday with Amazing photos - Vanguard Allure". Vanguard Allure. March 23, 2019. Retrieved August 6, 2022. 
  2. Izuzu, Chibumga (March 23, 2016). "6 things you should know about "Akun" actress". Pulse Nigeria. Archived from the original on February 10, 2020. Retrieved August 6, 2022. 
  3. "It is expensive to survive in Dubai — Regina Chukwu". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-11-04. Retrieved 2022-08-06. 
  4. THISDAYLIVE, Home - (October 15, 2020). "Regina Chukwu: I Used to Sell Wares By Road Side… Now I Live a Better Life – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. Archived from the original on August 6, 2022. Retrieved August 6, 2022. 
  5. Owolawi, Taiwo (April 28, 2022). "Mercy Aigbe and other top Yoruba Nollywood actors who are not Yorubas". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved August 6, 2022.