Richard Akinjide

Olóṣèlú

Oṣùọlálé Abímbọ́lá Richard Akínjídé,[[Adájọ́ Àgbà ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà] tí a bí ní ọjọ́ kẹrin, oṣù kọkànlá ọdún 1930, tí ó sì kú ní ọjọ́ kọkànle-lógún oṣù kẹrin, ọdún 2020(4 November 1930 - 21 April 2020)Ó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Naijiria.[1] , Ó jẹ́ ògbóǹtarìgì agbẹjọ́rò àgbà, olóṣèlú takuntakun àti oníṣòwò ńlá ní í ṣe. Gbogbo ènìyàn mọ̀ ọ sí Richard Akínjídé. Ó ti fì ìgbà kan jẹ́ mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ ní àkókò iṣejọba àwaarawa ẹ̀keji lẹ́yìn ìjọba ológun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, bákannáà ni ó sì jẹ́ Alákòóso Ìdájọ́ lábẹ́ ìjọba Ààrẹ Shehu Shagari.


Richard Akinjide
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1930-11-04)4 Oṣù Kọkànlá 1930
Ibadan, Nigeria
Aláìsí21 April 2020(2020-04-21) (ọmọ ọdún 89)
Ibadan, Oyo, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian

Awon itokasi àtúnṣe