Road to Yesterday (film)

Road To Yesterday jẹ́ fíìmù ajẹ́mọ́fẹ̀ẹ́ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó jáde ní ọdún 2015, èyí tí Ishaya Bako darí. Lára àwọn akópa inú fíìmù náà ni Genevieve Nnaji àti Oris Erhuero tí wọ́n jẹ́ olú ẹ̀dá-ìtàn, àti Majid Michel pẹ̀lú Chioma 'Chigul' Omeruah tí wọ́n ṣe ẹ̀dá-ìtàn mìíràn.[3] Fíìmù náà tí Genevieve Nnaji jẹ́ ọ̀kan lára àwọn aṣagbátẹrù ni fíìmù àkọ́kọ́ ti ó máa gbìyànjú láti gbé jáde.[4]

Road To Yesterday
Fáìlì:Road To Yesterday2015 poster.jpg
Theatrical release poster
AdaríIshaya Bako
Olùgbékalẹ̀Chichi Nwoko
Chinny Onwugbenu
Genevieve Nnaji
Àwọn òṣèré
OrinKulanen Ikyo
Ìyàwòrán sinimáIdowu Adedapo
OlóòtúChuka Ejorh
Ilé-iṣẹ́ fíìmùThe Entertainment Network (TEN)
OlùpínFilmOne Distribution
Déètì àgbéjáde
  • 27 Oṣù Kọkànlá 2015 (2015-11-27)
Àkókò91 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish
Ìnáwó₦30 million[1]
Owó àrígbàwọlé₦30,000,700[2]

Road to Yesterday sọ nípa ìtàn ọkọ àti ìyàwó kan tí wọ́n ti sọ ara wọn di àjèjì, tí wọ́n sì lérò láti ṣàtúnṣe sí ìgbéyàwó wọn ní ọjú-ọ̀nà láti lọ sí ètò ìsìnkú mọ̀lẹ́bí wọn kan.

Àwọn akópa

àtúnṣe

Ìgbéjáde

àtúnṣe

Ìlú Èkó ni wọ́n ti ya fíìmù Road To Yesterday.[5] Ìyàwòrán bẹ̀rẹ̀ ní oṣù February 2015.[6] Wọ́n gbe jáde pẹ̀lúàtìlẹ́yìn Africa Magic.[5] Road To Yesterday jẹ́ fíìmù àkọ́kọ́ tí Nnaji á kọ́kọ́ gbé jáde, àti fíìmù àkọ́kọ́ tí Ishaya Bako ṣàfihàn nínú rẹ̀.[7] Iye owó tí wọ́n fi ya fíìmù yìí ń lọ bí i ọgbọ̀n mílíọ́ọ̀nù náírà (₦30 million).[8]

Àwọn ìtókasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Badmus, Kayode (10 September 2015). "10 things you should know about Genevieve Nnaji's upcoming movie, Road to Yesterday". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 20 September 2016. 
  2. Odejimi, Segun (18 January 2016). "IN FULL: TNS Exclusive Report On Nigerian Cinema In 2015". TNS. Archived from the original on 21 February 2016. Retrieved 20 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "EXCLUSIVE: Oris Erhuero Speaks On Road To Yesterday, Nollywood". NAIJ.com. Retrieved 27 December 2015. 
  4. Ayalogu, Uju (20 November 2015). "EXCLUSIVE: Road To Yesterday Is An Introduction Of Who I Am – Genevieve". Retrieved 27 December 2015. 
  5. 5.0 5.1 Medeme, Vwe (1 October 2015). "Genevieve Nnaji shines in new movie, Road to Yesterday". The Nation. Retrieved 27 December 2015. 
  6. Abulude, Samuel (30 October 2015). "Genevieve Nnaji's 'Road To Yesterday' Screened Amidst Pomp And Pageantry". Leadership Newspaper. Retrieved 27 December 2015. 
  7. Tomilola (27 October 2015). "Ishaya Bako: The Director Of Genevieve Nnaji's Road To Yesterday Gives Us Exclusive Deets About The Movie!". 360Nobs.com. Retrieved 27 December 2015. 
  8. Badmus, Kayode (10 September 2015). "10 things you should know about Genevieve Nnaji's upcoming movie, Road to Yesterday". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 27 December 2015.