Ronald Ervin McNair, Ph.D. (October 21, 1950 – January 28, 1986) je omo Afrika Amerika asefisiksi ati arinlofurufu fun NASA. McNair ku nigba igbera Oko-alobo Ofurufu Challenger ni iranlose STS-51-L.

Ronald Ervin McNair
Arinlofurufu NASA
Orílẹ̀-èdèara Amerika
IpòAlaisi nigba iranlose Challenger
Ìbí(1950-10-21)Oṣù Kẹ̀wá 21, 1950
Lake City, South Carolina
AláìsíJanuary 28, 1986(1986-01-28) (ọmọ ọdún 35)
Cape Canaveral, Florida
Iṣẹ́ mírànPhysicist
Àkókò ní òfurufú7d 23h 15m
Ìṣàyàn1978 NASA Group
ÌránlọṣeSTS-41-B, STS-51-L
Àmìyẹ́sí ìránlọṣe