Ruth Kadiri
(Àtúnjúwe láti Ruth Kádírì)
Ruth Kádírì jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùkọ fọ́rán àwòkà eré ìtàgé àti olùgbéré jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ruth Kádírì | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | ọjọ́ Kẹrìlélógún oṣù Kẹta ọdun 1988 ìlú Benin |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | Mass communications,Yunifásítì ìlú Èkó |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásítì ìlú Èkó |
Iṣẹ́ | òṣèré orí-ìtàgé |
Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Ruth ní ọjọ́ Kẹrìlélógún oṣù Kẹta ọdun 1988 ní ìlú Benin tí ó jẹ́ olú-ìlú fún Ìpínlẹ̀ Ẹdó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó lọ sí Ilé ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ti Yábàá, tí ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Business Administration, bákan náà ni ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde gboyè àkọ́kọ́ ní Yunifásítì ìlú Èkó nínú ìmọ̀ ìbá ọ̀pọ̀ ènìyàn sọ̀rọ̀ (Mass communications) .[1]
Àwọn Ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ Ruth Kadiri, Naij