Ryutaro Hashimoto
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Japan
Ryutaro Hashimoto (橋本 龍太郎 Hashimoto Ryūtarō, tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1937[1] tí ó sì kú ní ọjọ́ kìíní oṣù keje ọdún 2006) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Japan tó di Alákòóso Àgbà ilẹ̀ Japan láti ọjọ́ kọkànlá oṣù kìíní ọdún 1996 títí di ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù keje ọdún 1998. Ó jẹ́ adarí ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó lágbára jù lọ ní orílẹ̀-èdè náà kí ó tó di pé ó kọ ìṣèlú sílẹ̀. Nítorí ìtìjú, kò kópa nínú ìdìbò gbogboogbò tí orílẹ̀-èdè Japan ní ọdún 2005. Ó kú ní ọjọ́ kìíní oṣù keje ọdún 2006 ní ilé-ìwòsàn kan ní ìlú Tokyo.[2][3]
Ryūtarō Hashimoto | |
---|---|
橋本 龍太郎 | |
Ryūtarō Hashimoto | |
Prime Minister of Japan | |
In office 11 January 1996 – 30 July 1998 | |
Monarch | Akihito |
Deputy | Wataru Kubo |
Asíwájú | Tomiichi Murayama |
Arọ́pò | Keizō Obuchi |
Deputy Prime Minister of Japan | |
In office 2 October 1995 – 11 January 1996 | |
Alákóso Àgbà | Tomiichi Murayama |
Asíwájú | Yōhei Kōno |
Arọ́pò | Wataru Kubo |
Minister of Finance | |
In office 28 January 1998 – 30 January 1998 | |
Alákóso Àgbà | Ryutaro Hashimoto |
Asíwájú | Hiroshi Mitsuzuka |
Arọ́pò | Hikaru Matsunaga |
In office 10 August 1989 – 14 October 1991 | |
Alákóso Àgbà | Toshiki Kaifu |
Asíwájú | Tatsuo Murayama |
Arọ́pò | Toshiki Kaifu |
Minister of Economy, Trade and Industry | |
In office 30 June 1994 – 11 January 1996 | |
Alákóso Àgbà | Tomiichi Murayama |
Asíwájú | Eijiro Hata |
Arọ́pò | Shunpei Tsukahara |
Minister of Transport | |
In office 22 July 1986 – 6 November 1987 | |
Alákóso Àgbà | Yasuhiro Nakasone |
Asíwájú | Hiroshi Mitsuzuka |
Arọ́pò | Shintaro Ishihara |
Minister of Health | |
In office 7 December 1978 – 9 November 1979 | |
Alákóso Àgbà | Masayoshi Ōhira |
Asíwájú | Tatsuo Ozawa |
Arọ́pò | Kyoichi Noro |
Member of the House of Representatives | |
In office 21 November 1963 – 11 September 2005 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Sōja, Okayama, Japan | 29 Oṣù Keje 1937
Aláìsí | 1 July 2006 Shinjuku, Tokyo, Japan | (ọmọ ọdún 68)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Liberal Democratic Party |
Àwọn ọmọ | Gaku Hashimoto |
Alma mater | Keio University |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Reed, Christopher (2 July 2006). "Obituary: Ryutaro Hashimoto". The Guardian. https://www.theguardian.com/news/2006/jul/03/guardianobituaries.japan.
- ↑ "Ryutaro Hashimoto". The Economist. 2006-07-11. Retrieved 2019-12-28.
- ↑ "Ryutaro Hashimoto, 68; Tough Former Prime Minister of Japan". Los Angeles Times. 2006-07-02. Retrieved 2019-12-28.