S'Nabou
Alima S'Nabou (tí a bí ní ọdún 1880) jẹ́ atúmọ̀ èdè (tí ó wá láti ibi tí Nàìjíríà wà lónìí) tí ó tẹ́lèé arìnrìn-àjò Faransé kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Lieutenant Mizon.
Ìtàn rẹ̀
àtúnṣeA bí Alima S'Nabou sínú ìdílé olóyè Konanki, nínú ìlú Igbobé, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Lokoja níbi tí odò Benue àti Niger ti pàdé. Ó gbó èdè Faransé, Gẹ̀ẹ́sì, àti àwọn èdè Niger míràn.[1] S'Nabou wà ní Assaba, nígbà tí ó pàdé Mizon[2] tí ìyá rẹ̀ sì sọ pé kí ó tẹ̀lé Mizon nínú ìrìn àjò rẹ̀ lọ sí Lokoja kí ó bà le rí bàbá rẹ̀, nítorí Mizon ń lọ sí Lokoja nígbà náà, S'Nabou jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́wàá sí mọ́kànlá nígbà náà. Ní Lokodja, S'Nabou sọ fún bàbá àti ìyá bàbá rẹ̀ pé òun fẹ́ tẹ̀lé Mizon nínú ìrìn-àjò rẹ̀ lọ sí Yola, olú-ìlú of Adamawa.[3][4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ (in it) Bollettino della Società africana d'Italia. La Società.. 1892. https://books.google.com/books?id=P3tbAAAAIAAJ&q=S%27Nabou&pg=PA172.
- ↑ "En Plein Soudan" (in fr). La Lecture: Magazine littéraire bi-mensuel 22. 1892. https://books.google.com/books?id=84kZAAAAYAAJ&q=S%27Nabou&pg=PA314.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:2
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:3
- ↑ Alis, Harry (1892). "Voyage dans l'Amadaoua par le Lieutenant de Vaisseau L. Mizon" (in fr). Le Tour du Monde 64: 225–288. https://books.google.com/books?id=xYXlAAAAMAAJ&q=S%27Nabou&pg=RA1-PA225. Retrieved 20 June 2021.